Home / Àṣà Oòduà / Olópàá tí owó tè nígbà tí ó n gba owó èyin ní ojà Yola.

Olópàá tí owó tè nígbà tí ó n gba owó èyin ní ojà Yola.

    Gégé bí ò n lò èro ayélujára tí ó gbé ní Yola tí ó pín ìròyìn ìsèlè yí se so, olópàá tí àwòrán rè hàn ní ìsàlè yí ní won yà nígbà tí ó n GBA owó èyin lówó àwon dérébà.

Bí ó bá wá di òla e ma ri àwon olópàá tí won a ma pariwo ” àyípadà bèrè láti òdò àwon”…

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Aáyẹ tí ó de bá àṣà

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà máa ń yí padà nípa aṣo wíwọ̀, ìgbéyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, lóde-òní, ètò ẹ̀kọ́ àti ìwà ọ̀làjú tó gbòde kan ti ṣe àkóbá fún àṣà ní àwọn ọ̀nà wọ̀nyí: (a) Ìwọsọ wa kò bójú mu mọ́. (b) Àṣà ìkíni wa kò ní ọ̀wọ̀ nínú mọ́. (d) Kí’yàwó ilé má mọ oúnjẹ ìbílẹ̀ ṣè mọ́. (e) A kò mọ ìtumọ̀ àrokò tí a ń kọ́ àwọn ọmọ wa mọ́. (ẹ) A kò fi èdè ...