Home / Àṣà Oòduà / Olùsò àgùntàn tí a mò sí pásítò Adeboye tí ó jé olórí àwon omo léyìn Jésù ti ìjo RCCG fún àwon akékòó ìmò adajó tí ó yege jùlo mérin ní Fìlà orí ri awon adájó àti aso won.

Olùsò àgùntàn tí a mò sí pásítò Adeboye tí ó jé olórí àwon omo léyìn Jésù ti ìjo RCCG fún àwon akékòó ìmò adajó tí ó yege jùlo mérin ní Fìlà orí ri awon adájó àti aso won.

Olórí àwon olùfokànsìn àti omo léyì jésù ti Ìjo àwon RCCG, gbogbo àgbáyé, Pásítò E.A Adeboye fún àwon akékòó tí won sèsè gboyè gégé bíi adájó mérin nínú ìjo rè ní àgbàlá HALL OF MERCY, Bwari ní ìpínlè Abuja, ní èbún.
Nítórí àgbàlá Hall of Mercy yíì kojú da ilé-èkó náà ní, ní Abuja, pasito Adeboye jé kí ó di mímò wípé, enikéni tí ó jé omo àgbàlá náà tí ó se àseyege láti ilé-èkó àwon adájó náa yóò gba àmì èye aso àwon adájó àti fìlà rè.
Àwon olóóri mérin náà ni:
Adewole Oluwatofarati
Ayomide Racheal Akinyemi
Onwioduokit Ugongabasa
Ananyi Emeka Emedo.
Obìnrin méta àti okùnrin kan.

About Awo

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo