Home / Àṣà Oòduà / Omo Oba Gwamnishu Harrison, tí won jígbé ,ké pé òun ń fi Nàìjíríà sílè 

Omo Oba Gwamnishu Harrison, tí won jígbé ,ké pé òun ń fi Nàìjíríà sílè 

 Olùdarí ilé-isé (CEO) ‘Behind Bar Initiative’, èyí tí ó pín àwòrán ara rè ní ibi tí ó gbé ń sunkún lórí èro ayélujàra (facebook). Ti so àsírí èròńgbà rè láti fi orílè èdè Nàìjíríà sílè lo sí ìlú òyìnbó (U. S. A), nígbà tí ó ti kó sí páńpé àwon tí ó jà á lólè lójó díè séyìn ní ìjoba ìpínlè Delta .
    Ó fi ègbékègbé pèlú àwon òdaràn yí nígbà tí  ó ń bò láti Agbor tí won  sì gba owó tí ó tó egbèrún lónà Igba (#200,000) lówó rè. Àwon òdaràn yí tún fi sí àhámó fún wákàtí díè tí won sì gba káàdì tí ó máa ń powó (ATM card) rè tí won sì bèrè nómbà àsírí tí ó fi máa ń gba owó jáde ní ilé-ìfowópamó (bank). Tí ó sì fun won, ni won bá gba gbogbo owó tí ó fi pamó pátápátá pèlú èro ìbánisòrò (phone) rè àti nkan míràn ni won gbà lo.
    Gégé bí ó se so, àwon ajínigbé yìí fun ní sìgà (cigarettes) pèlú Alomo kí ó tó di wípé won ja jù sílè ní àgbáríjo oko kan tí a mò sí Ughelli, ní ìpínlè Delta.
E wo ohun tí ó pín sí orí èro ayélujàra (facebook) Lánàá.
“E mo nkan tí ó duni jù? Kí o ní  èròńgbà lókàn kí o má mo bí o  se gbe jáde. Àkókò yí le gan fún mi. Kí olórun wà pèlú ìgbìmò egbé Kingsley Ughe àti egbé JLAA fún agbáterù yín.
    Modúpé púpò fún ìfé   yín JLAA ti Ughelli àti ti   Àsàbà.
  Kí ó tó di wákàtí Méjì-lé-láàdóta (48 hours) n o ti ma fohùn ní ìlú òyìnbó (U.S.A)……

English Version

Continue after the page break

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Aáyẹ tí ó de bá àṣà

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà máa ń yí padà nípa aṣo wíwọ̀, ìgbéyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, lóde-òní, ètò ẹ̀kọ́ àti ìwà ọ̀làjú tó gbòde kan ti ṣe àkóbá fún àṣà ní àwọn ọ̀nà wọ̀nyí: (a) Ìwọsọ wa kò bójú mu mọ́. (b) Àṣà ìkíni wa kò ní ọ̀wọ̀ nínú mọ́. (d) Kí’yàwó ilé má mọ oúnjẹ ìbílẹ̀ ṣè mọ́. (e) A kò mọ ìtumọ̀ àrokò tí a ń kọ́ àwọn ọmọ wa mọ́. (ẹ) A kò fi èdè ...