Home / Àṣà Oòduà / Omobìnrin tí kò ti dàgbà púpò ni àwon olùdábòbò yin ìbon pa ní Agbonchia , ní ìpínlè Anambra .

Omobìnrin tí kò ti dàgbà púpò ni àwon olùdábòbò yin ìbon pa ní Agbonchia , ní ìpínlè Anambra .

    Gégé bí èni tí ó pin sí orí èro ayélujára (Facebook) focuselema, àwon agbófinró ti jèbi pípa omobìnrin yí (tí àwon míràn ní okúnrin ni ) ti kú sí Agbonchia .

A kò mo ohun tí ó fa ìjàmbá.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo