Omokùnrin odún méwàá (10yrs) yí láti ìpínlè Anambrah ní orílè èdè Nàíjíríà , òun ni ó kó ilé yí orúko rè ni Chinecherewu. Mi ò le fun ní owó lásán ” ó n’ílò kí gbogbo ayé rí èyí.
Omokùnrin odún méwàá (10yrs) yí láti ìpínlè Anambrah ní orílè èdè Nàíjíríà , òun ni ó kó ilé yí orúko rè ni Chinecherewu. Mi ò le fun ní owó lásán ” ó n’ílò kí gbogbo ayé rí èyí.
Tagged with: Àṣà Yorùbá
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà máa ń yí padà nípa aṣo wíwọ̀, ìgbéyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, lóde-òní, ètò ẹ̀kọ́ àti ìwà ọ̀làjú tó gbòde kan ti ṣe àkóbá fún àṣà ní àwọn ọ̀nà wọ̀nyí: (a) Ìwọsọ wa kò bójú mu mọ́. (b) Àṣà ìkíni wa kò ní ọ̀wọ̀ nínú mọ́. (d) Kí’yàwó ilé má mọ oúnjẹ ìbílẹ̀ ṣè mọ́. (e) A kò mọ ìtumọ̀ àrokò tí a ń kọ́ àwọn ọmọ wa mọ́. (ẹ) A kò fi èdè ...