Home / Àṣà Oòduà / Oòni ti ìlú ilé-ifè darapò mó àwon mùsùlúmí ilé-ifè láti kírun ní ojó odún iléyà tí a mò sí Eid-el kabir.

Oòni ti ìlú ilé-ifè darapò mó àwon mùsùlúmí ilé-ifè láti kírun ní ojó odún iléyà tí a mò sí Eid-el kabir.

Gégé bí a se mò wípé àwon omo léyìn músùlùmí sèsè se àsekágbá odún won ní léyìn tí won ti gba ààwè séyìn léyìn bí osù mejì àti òsè mélòó sèyìn.

Oba Adeyeye Enitan Ogunwusi ti darapò mó àwon músúlúmi láti kírun papò ní ojó òdún yí, ìyàlénu nlá gbáà ni èyí jé fún àwon èèyàn.

Òtító kúkú ni wípé Oba kò ní èsìn kan ní pàtó, àti wípé Adeyeye jé kí a mò wípé bí oba se ba lórí ohun gbogbo ni Olódùmarè náa se ba lórí oba.
Èyí tí oba se yí jé kí a mò wípé òkan soso ni olórun, bí ó tilè jé wípé bí a se ñ kígbe pèé ló yàtò.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

kabiyesi

Èyí wuyì àbí kò wuyì?

Ẹ jẹ́ kí á ṣe Kábíyèsí fún Aláàfin Ọ̀wọ́adé, kí Èdùmàrè ó fi ìgbà wọn tu ìlú lára