Home / Àṣà Oòduà / Oritsefemi ná owó fún ìyàwó rè , Nabila Fash níbi ìgbéyàwó ìbílè rè.

Oritsefemi ná owó fún ìyàwó rè , Nabila Fash níbi ìgbéyàwó ìbílè rè.

Oritsefemi ná owó fún ìyàwó rè , Nabila Fash níbi ìgbéyàwó ìbílè rè.
Oritsefemi àti ìyàwó rè, Nabila Fash ti se ìgbéyàwó ní ilú èkó, e tún wo àwòrán Àkàrà òyìnbó won (Cake) tí tokotayà sì n wo ojú ara won tìfé tìfé, tìyìn tìyìn, tèye tèye. Tí won sì n wò ara won ní ìwò tokotayà.

 

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

kabiyesi

Èyí wuyì àbí kò wuyì?

Ẹ jẹ́ kí á ṣe Kábíyèsí fún Aláàfin Ọ̀wọ́adé, kí Èdùmàrè ó fi ìgbà wọn tu ìlú lára