Home / Àṣà Oòduà / ORÍKÌ OFA

ORÍKÌ OFA

Otunba Ikanni:
Iyeru okin olofa mojo,
Omo olalomi, omo a basu Jo o ko
Omo la a re, bu u re,
Okan o gbodo jukan,
Bokan bajukan Nile olofa mojo,
Ogun Oba ni i kowon ni roro,
IJA kan IJA kan,
Ti won ja lofa lojo si,
O soju ebe, o si soju poro ninu oko,
Iba soju oloko iba lawon,
Omo olalomi ni mori,
Mo dasa lami lapa,,
Iyeru okin ni mori,
Mo dasa lami lobe
Mi o pe e mo lami sugbon
E mo je ko jinle lapa mi,
Ijakadi loro ofa.
Koluwa ba da ilu ofa si

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

kabiyesi

Èyí wuyì àbí kò wuyì?

Ẹ jẹ́ kí á ṣe Kábíyèsí fún Aláàfin Ọ̀wọ́adé, kí Èdùmàrè ó fi ìgbà wọn tu ìlú lára