E dakun, e bawa fun arakunrin yii ni oruko kan ?
E dakun, e bawa fun arakunrin yii ni oruko kan ?
Tagged with: Àṣà Yorùbá
A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo
Okele rapata ! omi obe sororoooo !
Alaje kuuuuu
Efi le ebi ni o pa bo ya o gba awe biri biri 21 days e mon
wobia alaje iboko
shamu shamu oninu bi te ejo