Home / Àṣà Oòduà / Orunmila o jiire loni oooooo!

Orunmila o jiire loni oooooo!

Oluwo Agbaye;
Olori Awo Ode Isalaye;
Ifa a mo oni mo ola bi Oba Olodumare;
Igba eran ni a fi i bo’Fa;
Aboruboye!
Aboyeboru!
Aboyebosise!

cc- Yeyelufe IyaOgbe OmoEdu Oyewole

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

kabiyesi

Èyí wuyì àbí kò wuyì?

Ẹ jẹ́ kí á ṣe Kábíyèsí fún Aláàfin Ọ̀wọ́adé, kí Èdùmàrè ó fi ìgbà wọn tu ìlú lára