Home / Àṣà Oòduà / Owolabi Awodotun Aworeni omo Àràbà télè, Araba Adisa Aworeni, di Àràbà Àgbáyé.

Owolabi Awodotun Aworeni omo Àràbà télè, Araba Adisa Aworeni, di Àràbà Àgbáyé.

Gbogbo onísèsi àgbáyé ti darapò láti fi Omo Ekùn je Àràbà káàkiri àgbáyé.
Lóòótó òpò ni yóò ma rò wípé báwo ni ó se tún jé wípé omo Àràbà tí ó sísè náà ni ó tún jé, súgbón eni orí dá kò se é fi ara wé ni òrò náà, Owolabi Awodotun ti di Àràbà Àgbáyé kí ìgbà rè tù wá lára.

About Awo

x

Check Also

Aáyẹ tí ó de bá àṣà

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà máa ń yí padà nípa aṣo wíwọ̀, ìgbéyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, lóde-òní, ètò ẹ̀kọ́ àti ìwà ọ̀làjú tó gbòde kan ti ṣe àkóbá fún àṣà ní àwọn ọ̀nà wọ̀nyí: (a) Ìwọsọ wa kò bójú mu mọ́. (b) Àṣà ìkíni wa kò ní ọ̀wọ̀ nínú mọ́. (d) Kí’yàwó ilé má mọ oúnjẹ ìbílẹ̀ ṣè mọ́. (e) A kò mọ ìtumọ̀ àrokò tí a ń kọ́ àwọn ọmọ wa mọ́. (ẹ) A kò fi èdè ...