Peter Okoye tí ìnagije rè n jé Mr. P ti lé odún kan ní àná ó sì se ayeye ojó ìbí náà pèlú àwon ebí àti òré ní ilé rè. Gbajúgbajà òsèré, Omotola náà wà níbè.
Home / Àṣà Oòduà / Peter okoye se ayeye ojó ìbí rè nígbà tí ó pé odún mérìndínlógójì pèlú Omotola, Ebí àti òré.
Tagged with: Àṣà Yorùbá