Home / Àṣà Oòduà / Skolopad wo aso tí ó fi sósèjì se lo sí ibi láti gba àmì èye South African Feather.

Skolopad wo aso tí ó fi sósèjì se lo sí ibi láti gba àmì èye South African Feather.

   Àwòrán tí ó gba èro ayélujára kan ti àmì èye south African Feather ti odún yi ni ìmúra àwon èèyàn kò bójúmu rárá. Olórin kan ní South African “Skolopad” wo aso tí ó kún fún sósèjì àti àpò èédú fún ayeye àmì èye yí.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

kabiyesi

Èyí wuyì àbí kò wuyì?

Ẹ jẹ́ kí á ṣe Kábíyèsí fún Aláàfin Ọ̀wọ́adé, kí Èdùmàrè ó fi ìgbà wọn tu ìlú lára