Don't Miss
Home / Àṣà Oòduà / Somkele Iyama wo aso tí kò bo omú ló sí ayeye ìgbéyàwó BankyW àti Adesua Etomi.

Somkele Iyama wo aso tí kò bo omú ló sí ayeye ìgbéyàwó BankyW àti Adesua Etomi.

Arábìnrin tí ó rewà tí ti jé kí elénu sónu níbi aso tí ó wò tí ó dùn tí ó sì tún se òwón (n se ni ó dàbí eni wípé ó wo bùbá àti ìró)ó wò lo sí ìbí ìgbéyàwó BankyW àti Adesua Etomi nse ni ó dàbí egbin.

 

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo