Home / Àṣà Oòduà / Terry G se ayeye ojó ìbí fún omokùnrin rè, Teerex nígbà tí ó pé odún márùn-ún.

Terry G se ayeye ojó ìbí fún omokùnrin rè, Teerex nígbà tí ó pé odún márùn-ún.

   Omokùnrin Terry G, Teerex pé omo odún Márùn-ún bàbá rè sì se ayeye ojó ìbí náà fun pèlú àwon òrò tí ó dùn tí ó pín sí orí èro ayélujára (Instagram).

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Aáyẹ tí ó de bá àṣà

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà máa ń yí padà nípa aṣo wíwọ̀, ìgbéyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, lóde-òní, ètò ẹ̀kọ́ àti ìwà ọ̀làjú tó gbòde kan ti ṣe àkóbá fún àṣà ní àwọn ọ̀nà wọ̀nyí: (a) Ìwọsọ wa kò bójú mu mọ́. (b) Àṣà ìkíni wa kò ní ọ̀wọ̀ nínú mọ́. (d) Kí’yàwó ilé má mọ oúnjẹ ìbílẹ̀ ṣè mọ́. (e) A kò mọ ìtumọ̀ àrokò tí a ń kọ́ àwọn ọmọ wa mọ́. (ẹ) A kò fi èdè ...