Home / Àṣà Oòduà / Ti eba jabo si inu omi pelo ọkọ ayọkẹlẹ: Eleyi ni ona irọrun ti elefi gba emi yin la (Fidio)

Ti eba jabo si inu omi pelo ọkọ ayọkẹlẹ: Eleyi ni ona irọrun ti elefi gba emi yin la (Fidio)

Eleyi ni ona irọrun ti elefi gba emi yin la, ati ligba ti eba jabo si nu omi eyin ati ọkọ ayọkẹlẹ yin. A se iwadi wipe egbelegbe irinwo “400” awon eniyan ni ounku ni ododun lipa ijamba awon ati ọkọ ayọkẹlẹ won kiko si nu odo, ase iwa di wipe opolopo awon eniyah ni won ma un wole pelu oko ayokele na.  Eyii ni oun ti e ne se lati yo ara yin ninu ewu na, na i pe egbe omo ogun panapana tabi olopa, nipa wiwo fidio ti o wa ni sale oro yi, yi o je anfani fun yi nigba ti isele na ba se si yin.

 

English Version

Continue after the page break.

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

kabiyesi

Èyí wuyì àbí kò wuyì?

Ẹ jẹ́ kí á ṣe Kábíyèsí fún Aláàfin Ọ̀wọ́adé, kí Èdùmàrè ó fi ìgbà wọn tu ìlú lára