Home / Àṣà Oòduà / Won gbìmò láti da ilé mi wó, Dino Melaye se béè fún Yahaya Bello.

Won gbìmò láti da ilé mi wó, Dino Melaye se béè fún Yahaya Bello.

   Asojú ilé ìgbìmò asòfin Melaye ti tako Gómìnà ìpínlè Kogi Yahaya Bello tí ó gbèrò láti wó ilé rè ní ìpínlè Kogi. E kàá dáadáa.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Aáyẹ tí ó de bá àṣà

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà máa ń yí padà nípa aṣo wíwọ̀, ìgbéyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, lóde-òní, ètò ẹ̀kọ́ àti ìwà ọ̀làjú tó gbòde kan ti ṣe àkóbá fún àṣà ní àwọn ọ̀nà wọ̀nyí: (a) Ìwọsọ wa kò bójú mu mọ́. (b) Àṣà ìkíni wa kò ní ọ̀wọ̀ nínú mọ́. (d) Kí’yàwó ilé má mọ oúnjẹ ìbílẹ̀ ṣè mọ́. (e) A kò mọ ìtumọ̀ àrokò tí a ń kọ́ àwọn ọmọ wa mọ́. (ẹ) A kò fi èdè ...