Home / Àṣà Oòduà / Won we ose awure fomo Poli Ibadan

Won we ose awure fomo Poli Ibadan


Eniyan le fi ebi kose owo, sugbon ko rorun lati febi kawe. Wahala igo ni o pa alasuota. Ise akanse, ka ji kawe loru, lo soke lo sode, ka sare wo kilaasi losan pon ganrin-ganrin ni o je komo ile iwe o nisimi.

Bi won ba wa jade, ayo nla ni.

Okan ninu awon omo Poli to wa ninu Ibadan, Shina Shiba, lo se afihan foto ati akole yii: “Finally log out from polystressnic(polytechnic) Ibadan” Adura mi wi pe ki Edua oke ba mi so ona won dayo, ki won ri taje se, ki ona won o la sire.

Ase !

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

kabiyesi

Èyí wuyì àbí kò wuyì?

Ẹ jẹ́ kí á ṣe Kábíyèsí fún Aláàfin Ọ̀wọ́adé, kí Èdùmàrè ó fi ìgbà wọn tu ìlú lára