Home / Àṣà Oòduà / Yakubu Gowon lo kí Shehu Shagari. 

Yakubu Gowon lo kí Shehu Shagari. 

Olórí ìpínlè télè (former head of state) General Yakubu Gowon lo kí Ààre ti télè Shehu Shagari ní ilé rè ní Sokoto.
Gómìnà Tambuwal sìn-ín lo pèlú Olórí àlùfáà Ìjo Catholic ti Sokoto,  Bishop Matthew Hassan kukan àti àwon ènìyàn láti àgbáríjo aládùráà ní orílè èdè Nàìjíríà tí Gowon “Gowon’s NIGERIA PRAYS organization…

Continue after the page break for English version

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Aáyẹ tí ó de bá àṣà

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà máa ń yí padà nípa aṣo wíwọ̀, ìgbéyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, lóde-òní, ètò ẹ̀kọ́ àti ìwà ọ̀làjú tó gbòde kan ti ṣe àkóbá fún àṣà ní àwọn ọ̀nà wọ̀nyí: (a) Ìwọsọ wa kò bójú mu mọ́. (b) Àṣà ìkíni wa kò ní ọ̀wọ̀ nínú mọ́. (d) Kí’yàwó ilé má mọ oúnjẹ ìbílẹ̀ ṣè mọ́. (e) A kò mọ ìtumọ̀ àrokò tí a ń kọ́ àwọn ọmọ wa mọ́. (ẹ) A kò fi èdè ...