Home / Àṣà Oòduà (page 103)

Àṣà Oòduà

Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.

Ifa naa ki bayi wipe

| |   | | |   | | |  | | | |   | YORUBA VERSION: Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku isimi oni, emin wa yio se pupo re laye o ase. Odu ifa OKANRAN IRORUN ...

Read More »

Awada Kerikeri

Ebi de, ebi mama de ooo nibo wonti nta oka nile yi Ebami wabo wa oo

Read More »

Ogulutu Oro Toni – 16.06.2016

‎SI GBOGBO OBINRIN‬ Hummm obinrin sowa nu oni oko(husband) o feran oun oti gbagbe pe iwa lewa omo eniyan ‪abi‬ Oti gbagbe wipe bi eso oko(farm) ba da ladaju eye oko lasan ni mo pada mu ru won je. Wonyi ...

Read More »

ko ko ko. Tani yen o?

Awa ni O! Eyin Wo? Awa Anu,Ire,Iyanu,Owo,OmO, Ayo,Ibukun,Alafia,Igbega,Aseyori,Aabo,Idunu,Itesiwaju, Ojurere Olorun at Emi gigun. Kini e wa o?. Awa lati wa ba iwo ati ebire/ore eyi ti o fe fun ire gbe lati odun yilo atii titi laiye… Ifa kan so ...

Read More »

Arewa Asa Toni

Ayeye Ojo Ibi Iyawa Toyin Adewale Ojo ibi se koko Ojo ibi se pataki eo ni mo Ojo ibi yin saburu,Ododun ni sapo nruwe Ododun ni mariwo yo Ododun la nri omo obi lori ate, emi yin o se opo ...

Read More »

Iwure Owuro 12.06.2016

E MAA WI TELE MI : *Ori mi wa gbe mi leke abinu eni. *Ori mi ko ni gbabode ibi. *Oloore mi ko ni ri mi sa *Oluwa so egan mi dogo. *Edumare wa fi ibukun sinu ise mi *Lojo ...

Read More »

Ire otun, ire osi, ire niwa..Iree o

Iree! Apa mejeeji l’eyele fi n ko’ree wo’le. Ire otun, ire osi, ire niwa, ire l’eyin, ire Olokun, ire Olosa, ko mi a da giriri wole to wa wa! Aase!

Read More »

Idile Alayo Toni 09.06.2016

Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wipe a ku dede asiko yi, mo si ki awa ololufe eto Idile Alayo wipe e ku abo sori eto wa, eto yin, eto Idile Alayo ti ose yi. ...

Read More »

Odo Iwoyi – 3

Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wipe a ku dede asiko yi, mo si ki awa ololufe eto Odo Iwoyi wipe e ku abo sori eto wa, eto yin, eto Odo Iwoyi ti ose yi. ...

Read More »

Sun re O! Henrietta Kosoko

Hummmmmm Erin wo ajanaku tisun bi Oke eyin ka ile Erin wo porogodo,okoko fo omi okoko danu haaaa sebi eyan Se nku re Oga oooo…….Orun mo kanju Ojo eda oni se ooo

Read More »