Home / Àṣà Oòduà (page 123)

Àṣà Oòduà

Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.

Joke Muyiwa lori eto Gbajumo Osere

Read More »

Baba Gboin (Bashiru Adisa) lori eto Gbajumo Osere

Read More »

Tafa Oloyede (Adewunmi Adewoye) lori eto Gbajumo Osere

Read More »

Small Doctor lori eto Gbajumo Osere

Read More »

YK Ajao (Yekini Kolawole Ajao) lori eto Gbajumo Osere

Read More »

Adebori ilu loruko tia pe ifa…

Adebori ilu loruko tia pe ifa, Isinmi obarakale loruko tia pe orisala, Akorere wa bami loruko tia pe eyin iya mi osoronga, Meta niyin ni ojo ti e ti ikole orun bo wa sile aiye. Emi Olabisoyemansur ni pe yin ...

Read More »

E Jowo Ninu Iyabo Ojo Ati Mercy Aigbe Tale Feran Ju?

Read More »

Ambode ti yan oga agba tuntun fun ileewe LASU

Gomina Ipinle Eko, Ogbeni Akinwunmi Ambode ti yan Ojogbon Olanrewaju Fagbohun gege bi oga agba tuntun fun ileewe Ifafiti ti ipinle Eko, LASU. Ikede yii lo waye ninu atejade ti komisanna fun eto iroyin ati agbekale ilana, Ogbeni Steve Ayorinde ...

Read More »

Awon tisa ipinle Kwara taku sori idasesile ti n lo lowo

http://www.olayemioniroyin.com/ Idasesile awon oluko alakobere to ti bere lati ojo Aje to koja yii nipinle Kwara ni awon egbe oluko ti temu mo o wi pe yoo si ma tesiwaju ayafi ti ijoba ba san gbese owo osu meta ti ...

Read More »

Ohun to pada sele si maanu to lo gbadun ara re nile asewo buru jai

Maanu yii lo lo gbadun ara re nile asewo kan niluu Benin. Aisanwo leyin igbadun lo di ohun ti won da igbati jo fun un.

Read More »