Home / Àṣà Oòduà (page 134)

Àṣà Oòduà

Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.

E ba wa dasi oro yii: Ninu ipo ati iya eni, e wo lo gaju?

Leyin ti won fi Sanusi je Emir tilu Kano, oba. Ilu Kano si gba wi pe oosa ajiki bi iya ko si laye. Eleyii lo mu gomina banki agba ile yii nigba kan ri teriba niwaju yeye to bi i ...

Read More »

Eto idibo gomina ipinle Kogi di fopomoyo

*Faleke n binu, ara ilu n sofo *Iwe ofin ruju mo awon amofin loju *Won tun ni kan fomo Audu je gomina apapandodo Leyin iku Abubakar Audu, oludije fun ipo gomina labe egbe oselu APC nipinle Kogi, eni to jade ...

Read More »

Se Gbenga Adeboye lo ko Wale Dada nise sorosoro?

Lori eto Miliki Express lori telifisan Orisun ni won ti gba Adewale Dada TheGood gege bi alejo pataki ni nnkan bi osu meloo kan seyin. Lori eto naa ni won ti beere lowo enikan to ti fi igba kan dije ...

Read More »

Yemi Osinbajo: Ori taa fi sewe

Igbakeji Aare, Yemi Osinbajo nigba to wa nile iwe alakobere Corona School, Lagos.  Awon Yoruba bo, won ni ori taa fi sewe kii kuro lorun eni taa ba dagbalagba.

Read More »

E wa wo ohun ti oludije ipo gomina n se lagbala pelu aya re.

Eng Seyi Makinde, okan ninu awon oludije ipo gomina nipinle Oyo, labe egbe oselu SDP ninu eto idibo odun 2015 to waye ni yii pelu aya re.  Gege bi iwadii Olayemi Oniroyin lati enu awon to sun mo eni ti ...

Read More »

Atelewo eni ki i tanni i je

Awon Yoruba bo, won ni amukun-un eru re wo, o ni oke le n wo, e wole. Ojuse awon obi ki i se lati pese ohun ti awon omo won ba n fe nikan, bikose lati sakiyesi iru ebun ti ...

Read More »

Kini ijoba n se nipa awon ti n se ayederu?

Orisun iwe Iroyin Iroyin yii kii se tuntun, yoo si ti to bi osu kan o le die ti asiri awon to n se ayederu elerindodo Coca Cola ti jade. Sugbon iru awon iroyin bayii, a kan maa n gbo ...

Read More »

Foto: Saheed Osupa Mr Designer

Awon eniyan oba ni Osupa ti mura tan lati gbe awo orin re tuntun jade. E le ka iroyin naa NIBI. Eniwee, mo sakiyesi wi pe awon aso okeere maa n mu oju osupa dabi odomode nigba ti awon aso ibile ...

Read More »

Fila o dun bi ka moo de…

Oni fila yii

Read More »

Idi pataki meta ti ko fi ye ka maa fi ehin je eekanna

1. Ehin le yingin tabi ki die kan lara ehin wa: Nigba mi-in ti a ba n gbiyanju lati fi ehin ge eekanna wa, ehin wa le lura won lojiji, eleyii si le fa ki ehin yingin legbe kan tabi ...

Read More »