E gbo, taani igo rewa ju loju re? Se Toyin ni abi Muyiwa Ademola, abi Eniola nigo naa ye ju?
Read More »#Our5K ti da wahala sile lori ayelujara: Ile Igbimo Asofin ni wahala naa ti bere
#Our5K ti da wahala sile lori ayelujara: Ile Igbimo Asofin ni wahala naa ti bere Olayemi Olatilewa Lojo Wesde to koja yii nile igbimo asofin agba to kale siluu Abuja gbegi dina sisan owo egberun marun-un fun awon odo ile ...
Read More »Igbeyawo Asofin Moji Lawal niluu Eko leku!
Arabirin Moji Lawal, okan ninu awon omo ile igbimo asofin ipinle Eko segbeyawo alarinrin lopin ose to koja yii pelu oko re, John Paul to je onisowo pataki. Arabirin Moji, eni to je obirin akoko ti o ma soju ekun ...
Read More »E wo ohun ti Gomina Fayose n se laaarin oja
Gomina Ayodele Fayose da moto re duro loja Bisi to wa ni Ipinle Ekiti lati teti si edun okan iya arugbo yii nipa ohun ti won fe ki ijoba o se fun won. Gomina fara bale lati gbo gbogbo ohun ...
Read More »Igbe aye Oba Lamidi Olayiwola Atanda Adeyemi dun bi oyin
Laipe yii ni Oba Lamidi Adeyemi, Alaafin Oyo pe eni odun metadinlogorin. E le ka iroyin naa nibi: Lara awon foto ojo ibi baba mi-in to te wa lowo ni eyi ti baba ya pelu Olori Badirat Adeyemi, olori baba ...
Read More »Iyanu sele leyin odun meta
Odun meta lo gba arakunrin yii lati yii igbe aye re pada si bo se fe. O salaye wi pe alaafia ti de ba ara oun bayii, oun le mi daada bakan naa ni oun jafafa ju ti tele lo. ...
Read More »Foto tuntun: E wo ohun ti Mikel Obi n se loju titi
Mikel Obi ati iyawo re, Olga pelu awon omo ibeji. #EbiAlayo
Read More »Awon egbe APC ti ko lati mu ileri won se #Our5K
Nje e ti gbo? Awon omo ile igbimo asofin agba l’Abuja ti won je ti omo egbe APC ti tako aba eleyii to wa nibamu pelu ileri ti Aare se lati maa san egberun marun-un owo naira (5K) fun awon ...
Read More »“Ni Akute, awon ota ni won ba Amosun loruko je” Ijoba ipinle Ogun
Olayemi Olatilewa Ile ise ijoba ipinle Ogun ti pe akiyesi awon ara ilu si iroyin eleje kan ti iwe iroyin kan gbe jade wi pe wahala wa laaarin awon oloja ti won gbe ni agbegbe Akute ati gomina ipinle Ogun, ...
Read More »Iwon ese bata kan pere: E kaabo sinu osu tuntun
#Ogulutu #4 Eyin eniyan mi, n maa ki yin kaabo sinu osu tuntun pelu itan Ogbeni Darby omo ilu Amerika to ti n tawo-tase ninu mi fun igba pipe. Itan aroko ko, bee si ni mi o ni fe ki ...
Read More »