Ekáàrọ̀ọ́ ẹ̀yin ènìyàn mi, aojiire bi? Oni a sanwa o, ao rí tiwa se loni, gẹ́gẹ́bí òní ṣe jẹ ọjọ́ àíkú, gbogbo wa koni kánjú ku lágbára Olodùmarè àṣẹ.E jékí a fi odù ifá mímọ́ ọ̀bàrà bubu yi ṣe ìwúre ...
Read More »Home / Àṣà Oòduà (page 27)
Fayose kò mo̩ bò̩ò̩lì àti àgbàdo je̩ tó mi,àmó̩… – Fayemi
Gomina ipinle Ekiti, Dr Kayode Fayemi lo n salaye yii nibi eto ori telifison Kan ti arabinrin Morayo Afolabi n dari re.Leyin ti gomina dahun orisiirisii ibeere ni arabinrin naa wa tun beere asepo to wa laarin oun ati gomina ...
Read More »Ti o ba ka iwe yii fi ara e han
Gege bi Omo Oodua Rere, Nje E Mo Oruko ti won pe kokoro yi ?
Kini Oruko ti won pe kokoro ti o wa ninu aworan oke yii ?
Read More »Awa Omo Oudua Rere: E Da Epa Owe Kan To Ba Oro Aja Lo
Owe Yoruba
Read More »Òṣèré wo ni ẹ fẹ́ràn jù nínú àwọn àgbà osere meji yi?
E ba mi Pari owe yii
E fun mi ni owe to ni Ile(house) ninu ?
Edakun gbogbo ile, e fun mi ni owe to ni ile(house) ninu. E seun.
Read More »Owonrisogbe – Ifá Naa Ki Bayi Wipe: Biijo biijo…
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a si tun ku orire osu Ògún tuntun to bawa layo ati alaafia, osu naa yio sanwa sowo, somo, sile kiko, moto rira, ire oko/aya ati aiku baale oro yio ...
Read More »Iya mi Osun Sengese
Iya mi Osun Sengese Ladekoju Ebora ti n gbenu omiLagbolodo,Iwo ni mo nkee si o.Osun ma n bo oYago lona o.
Read More »