Oba Aworeni Makonranwale Adisa ti re ìwàlè àsà, baba ti lo bá àwon baba ńlá rè. Olúsèse, Àràbà àgbáyé ti dágbére wípé Ó dígbà fún aráyé, baba ti lo rè é bá àwon baba ńlá rè ní ìwàlè àsà. Ó ...
Read More »Eka-èkó tí ó ń kó nípa Àsà ti ilé-èkó gíga ifáfitì Obafemi Awolowo university se odún oúnje àti ìdánimò (festival of food and identity).
Ni Àná tí ó jé ogbòn-ojó osù keje odún 2018, ni eka-èkó ìmò àti Àsà ti ilé-èkó gíga ifáfitì ti Obafemi Awolowo university se odún oúnje àti ìdánimò. Òjògbón Wole Soyinka kò gbéyìn rárá Baba náà péjú pésè níbi odún ...
Read More »Àgbàrá òjò ti gbalé gbalè ní ìlú ilé-ifè ní àná tí Òpò akékòó kò sì rí àyè lo sí ilé-èkó.
Gégé bí a ti mò wípé ilé-ifè jé ìlú tí ilé-èkó gíga wà, tí ó sì kún fún àwon akékòó bíi àwon akékòó ilé-èkó gíga ifáfitì ti Obafemi Awolowo university (OAU) àti ilé-èkó gíga ifáfitì ti Oduduwa university ilé-ifè ...
Read More »Simi kúnlè ní orí ìtàgé láti kí ògbóntarìgì olórin tí a mò sí Lágbájá, nígbà Ó ń dá àwon èèyàn lárayá lówó.
Simi tí síde ayeye tí Jannie, Jazz àti Whisky pè ní ìlú Abuja ní alé ojó náà, Simisola jungle ní orí ìtàgé láti kí eni ńlá, èníyàn pàtàkí àti gbajúgbajà olórin láti dá àwon èníyàn lárayá papò. Ògbóntarìgì olórin tí ...
Read More »Omiyalé, àgbàrá ya sóòbù ní ìlú ilé-ifè.
Ní òwúró ojó àíkú tí se èní,ojó kokàndínlógbòn osù keje odún 2018 ni òjò yí bèrè tí ó sì kò tí kò dáké di bíi agogo márùn-ún ìròlé. Èyí fa kí àgbàrá ya wo ilé tí ó pò ní òpópónà ...
Read More »Obàtálá
Obàtálá (Ìwà) Amúyan abìtanná yanranyanran Adia’fun orunmila babá o tanná fórìsà riwa Ebo lawo ni kose Ógbébo órúbo Ógbèrù ótèrù Njé ifá tan sílé, èdú tan sónà Tan ni o mòpé ina ire lope ntan Bàbá arúgbó that: Sleeps in ...
Read More »ÀWỌN JAGUNJAGUN WA
Ó yá, Ẹ jẹ́ á sàm̀bátá àwọn jagunjagun wa. Ẹ jẹ́ ká f’orin ọgbọ́n yẹ̀ wọ́n wò, Ká mọ rírì isẹ́ wọn t’ó yakin. Pàtàkì l’àwọn ológun lórílẹ̀-èdè yìí; Ișẹ́ takuntakun ni wọ́n kúkú ń ṣe. Mo kírà f’áwọn sójà ...
Read More »Omokùnrin odún méèédógún tí orúko rè ńjé Okorogheye David ni ó peregedé jùlo nínú ìdánwò àsekágbá ti ilé-èkó
Omokùnrin odún méèédógún yí gba máàkì tí ó pò jùlo nínú ìdánwò àti wo ilé-èkó gíga ifáfitì tí ó sì gba púpò jùlo nínú WAEC. Omokùnrin yí gba àmì A nínú gbogbo ìdánwò tí Ó se fún WAEC tí Ó ...
Read More »ÈDÈ YORÙBÁ
ÈDÈ YORÙBÁ Èdè Yorùbá ṣe pàtàkì; Ó ṣe kókó. Ẹ̀yin ọmọ Oòduà, Ẹ jẹ́ ká máa rọ́jú s’èdèe wa. Èdè òǹluko kọ́ l’èdèe Yorùbá. Èdè tó gba’yì tó gb’ẹ̀yẹ ni. Àìkọ́mọ l’áhọ́n-ìbílẹ̀, Ní sábàbí ìwà ọ̀yájú. Ọmọ yín jí ní ...
Read More »Won ti ojà ní Abeokuta láti fi se àpónlé fún Oba won tí ó di olóògbé.
Ojà tí ó wà ní ìlú Abeokuta ní won tì pa pátápátá ní àná, won se èyí láti fi se àpónlé Oba won tí ó wàjà eni tí a mò sí Oba Halidu Laloko (MFR) tí ó jé Agura ti ...
Read More »