Gégé bí èni tí ó pin sí orí èro ayélujára (Facebook) focuselema, àwon agbófinró ti jèbi pípa omobìnrin yí (tí àwon míràn ní okúnrin ni ) ti kú sí Agbonchia . A kò mo ohun tí ó fa ...
Read More »Kenneth Okonkwo àti omo rè yo ní àrà òtò.
Bí eni tí ó pin se so wípé . “Àwon òbí ní láti sóra fún àwon nkan tí won bá n se n’íwájú àwon omodé nítorí won n wò wá”.
Read More »Won dí afárá Niger nítorí ètò ìdìbò tí ó n lo lówó ní Anambra.
Afárá tí kò fi ìgbà kan dúró tí ni won ti tì látàrí ìdìbò tí ó n lo lówó ní Anambra.
Read More »Nabila Fash pe àwon obìnrin níjà bí won bá le ya àwòrán làì kunjú bí ti tò òun.
Bí Nabila, ìyàwó olórin kan, Oritsefemi se pín àwòrán tí kò ti kunju tí ó so wípé òun yà léyìn ìdárayá ní òwúrò àná.
Read More »Gómìnà Obina náà dìbò níbi ìdìbò Anambra.
Gómìnà Anambra Willie Obiano náà dìbò fún ara rè ní Otuocha ward 1 unit 004.
Read More »Àwon òdó ní Anambra pa màálù láti gbádùn ojó Nsala won nígbà tí won kò sì lo fún ètò ìdìbò.
Àwon òdó míràn gbádùn Nsala won, gégé bí won se pín sí orí èro ayélujára.
Read More »E ye àwon egbé ìyàwó Adesua Etomi wò.
Adesua ti se tán láti se tán láti se ìgbéyàwó. Ìgbéyàwó rè ti è ti súmón etílé.
Read More »Omo egbé PDP tí ó n lo fún ipò , Obaze ti lo dìbò fún ara rè.
Omo egbé PDP tí ó n lo fún fún ipò níbi ìdìbò Anambra Oseloka Obaze níbi tí ó ti dìbò fún ara rè.
Read More »Ayé k’áye ni eléyìí Ooo..
Wón so ìran adúláwò dí eranko, kódà isé tí eranko kò le jé ni won n fi won jé . Won n lo ìran adúláwò n’ílò Ku lò.
Read More »Kí olódùmarè sàánú ìran adúláwò.
Kì í kú se wípé olórun d’àwa l’ájá béè kò dáwa l’éranko bí kò se wípé ó dáwa láláwò dúdú, ó sì dá àwon kan pupa. Sùgbón kò fi enìkan se erú enìkan.
Read More »