Home / Àṣà Oòduà (page 74)

Àṣà Oòduà

Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.

Àwòrán ìsìnkú Odudu Davis, olóòpá tí ìbon àwon olóòpá ojú omi bà tí ó sì kú ní ìpínlè calabar. 

  Ní’sàlé ni àwòrán ìsìnkú olóyè nínú ológun (Corporal)  Odudu Davis tí ìbon pa nígbà tí osù kàrún di ogbòn ní inú odún yìí (30/5/2017)láti owó àwon olóòpá ojú omi (naval officer) nígbà tí àwon olóòpá àti àwon olóòpá ojú ...

Read More »

A kú àyájó odún *Òmìnira* ti *orílè Èdè Nàìjíríà* ?? lónìí ooo.

A kú àyájó odún *Òmìnira* ti *orílè Èdè Nàìjíríà* ?? lónìí ooo. Èmí wa yóò se púpò rè láyé. E jòwó, e má sì gbàgbé láti se *ìwúre* fún orílè èdè *Nàìjíríà* ?? nítorí wí pé *”Ìròrùn igi ni ìròrùn ...

Read More »

Arewa Toni

Read More »

Oga Bello àti iyalode Binta Mogaji

Awon agba osere apanilerin meji

Read More »

Ìyàwó mi dára sùgbón kò n’ìfé ìbálòpò léyìn ìgbeyàwó.

Ìyàwó mi dáa tí mo sì le pè ní aya rere sùgbón kìí gbà kí á bá ara wa lò nígbà tí ó ye, lóòtó aní omo okùnrin pèlú obìnrin. E jò ó kí ni mo le se? Mo ti ...

Read More »

Kílódé tí àwon omoge fi n’ìfé àwon tí ó ti n’íyàwó.

E jòwó mo fé kí e dá mi lóhùn dáadáa. Gbogbo àwon Òré mi tí ó ti n’íyàwó n’ílé ni òpò obìnrin ń súré tè lé, tí ó sì jé wípé àwon àpón bí ti àwa yí obìnrin díè ni ...

Read More »

Odu ifa IROSUN OSE/ALAJE

Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku isinmi ana o, Olorun eledumare yio jeki aje fi ile wa se ibugbe loni o ase. Odu ifa IROSUN OSE/ALAJE lo gate laaro yi, ifa yi fore aje lopolopo fun akapo ti o ...

Read More »

Musa Musa, olóòpá tí ó fó ilé Jonathan.

Àwon Agbófinró ti rí àwòrán olóòpá kan tí ó jé atónà fún àwon ìgárá olóshà tí ó fó ilé Ààre télè Goodluck Jonathan ní Gwarimpa Abuja. Musa tí a gbé lo sí ilé-ejó gíga díè (magistrate) ní ojó ìségun tí ...

Read More »

Omokùnrin kan tí orúko rè ńjé Charlyboy subú lulè nígbà tí won ń se àtakò Buhari. 

 Àmóhùnmáwòrán Channels ti pín fídíò tí ó se àfihàn omokùnrin kan tí ó ń jé Charlyboy nígbà tí ó subú lulè nígbà tí won ń tako Buhari lówó ní ìlú Abuja láàárò òní. Àwon Agbófinró fín tajútajú àti omi láti tú ...

Read More »

Òrékùnrin mi ń bínú sími.

E jòwó, mo fé àmòràn lórí ohun tí ó ye kí n se, osù kewàá rèé tí mo ti mo Òrékùnrin mi, a sì ní ìfé ara wa, sùgbón Òrébìnrin rè télè sì ń dàá láàmú, èyí sì ń jé ...

Read More »