Ori Onise Apere Atete gbeni ju Orisa Ori atete niran Ori lokun Ori nide Ko si Orisa ti dani gbe leyin Ori eni Ori ni seni ta a fi dade owo Ori ni seni ta a fi tepa ileke woja ...
Read More »Ikoja aaye pelu aimo iwon ara eni…
Mejeeji ko papo amoo won maa n wo tele ara wo leyin ni. Yorubo won ni, ikoja aaye nii mu ki fulani o kiri odo iyan. Aimo iwon ara eni naa nii sii muki abuke o ko ise atun’ko se. Emo ...
Read More »Iwulo Ewe To Wa Ninu Aworan Yi Ninu Odu Ifa OGBEYONU,
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a sin Ku isimi oni emi wa yio se pupo re laye o ase. Loni mofe ki a mo iwulo ewe to wa ninu aworan yi ninu odu ifa OGBEYONU, ...
Read More »Iwulo Ewe To Wa Ninu Aworan Yi Ninu Odu Ifa EJIOGBE
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, mogbaladura laaro yi wipe eledumare koni jeki enikookan wa jaye inira loni ase. Laaro yi mo nfe ki a mo iwulo ewe to wa ninu aworan yi ninu odu ifa ...
Read More »“Kíní ó ye’kú nùn l’Órí Awo?
Èjì Òyè Ifá ní ó ye’kú nùn l’Órí Awo What will avert death away from Awo? Èjì Òyè Ifa will avert death away from Awo.” ~Owó
Read More »Danrogbo ati Opapa
Danrogbo, Opapa, Owarowaro, Danrogbo ni won n pe iku, Opapa ni won n pe arun, Owarowaro ni won n pe ekun, Igbo loni ki ori wa gbo kaka di ale, Bi igbin ba dagba,a darugbo kegekege, Ki iku ma ji ...
Read More »Ìrosùn Méjì
Whoever this Odu is revealed to maybe during Ifá consultation, ìtènifá or Ìséfá, this person needs to offer Ebo and feed Ifa. One of the biggest problem of this person is lack of wealth. This person complains alot about not ...
Read More »Ori Eni Lawure Eni O…
Ori Eni Lawure Eni O Ori Eni Lawure Eni Mo ji lowuro mo dewo mori O Ori Eni Lawure Eni… Ki Ori wa ma sowa nu ooo… Ase Ire O! Translation One’s Spiritual/Inner head is his/her super spell(2ce) I woke ...
Read More »Eku Apere Ninu Ile Nla
Moki gbogbo apapo ojogbon awo mimo lagbaiye ninu ile nla I.K.O. nla wayi ooo Wipe :- (.KINNIHUN ORUNMILA OO.) (Ilosiwaju ishese lo jemi lo gun ooo) EJOWO OO E NPE MI SI AKIYESI Oruko mi ni iyin oluwa moje enikan ...
Read More »Orunmila O jiire l’oni o! Bi Àlà tii ji l’Ode Akure!
Okanran Meji II II II II II II I I Ifa ni: Bi a ba ti ko ni bee ni a n ki ni Bi a ba ti ki ni bee ni a n je ni Orunmila pele o ...
Read More »