*Ìwà rere*Iléere ní ẹ̀ṣọ́ nínúÌwà’bàjé ní jẹ́ k’ọ́mọ o j’ìyàẸwúrẹ́ ya aláìgborànÀgùntàn jẹ́ oníwàpẹ̀lẹ́Adígbánnákú ṣẹ̀yìn gákangàkan Iléere ní ẹ̀ṣọ́ nínúÌwà rere lẹ̀sọ́ ènìyànÌwà rere ni òbí ní,tí wọ́n fi ń ǹpé ní òbí rereÒbí rere ló le kọ́mọ ní’wà rereÒbí ...
Read More »Èeyàn 239 míràn ni àrùn Covid-19 lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà
Èeyàn 239 míràn ni àrùn Covid-19 lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà À fi kí Ọlọ́run sàánú wa lórí àjàkálẹ̀ àrùn apinni léèmí kòrónáfairọ̀ọ̀sì yìí tó ń gbomi lójú t’olórí t’ẹlẹ́mù, bí Ìjọba orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí tún kéde àwọn ènìyàn tuntun tó ṣẹ̀ṣẹ̀ kó ...
Read More »Kofi 19 dẹ́yẹ sí ìpínlẹ̀ Kogi àti Cross River –Osagie
Kofi 19 dẹ́yẹ sí ìpínlẹ̀ Kogi àti Cross River –Osagie Àwámárídìí ni iṣẹ́ Elédùwà, ṣùgbọ́n ọmọ èèyàn lọ́pọ̀ ìgbà má a ń fẹ́ tú fín ìn ìdí i kóòkò láti mọ kín gán án ní ń gbénú-un rédíò fọhùn. Bí ...
Read More »Ènìyàn 148 míràn lárùn Covid-19 ní Nàìjíríà–Àjọ NCDC
Ènìyàn 148 míràn lárùn Covid-19 ní Nàìjíríà–Àjọ NCDC Ó ti pé ẹgbẹ̀rún mẹ́ta àti márùndínládọ́jọ èèyan tó ti ní àrùn apinni léèmí yìí ní Nàìjíríà. Ìpínlẹ̀ Èkó ló ṣì ń léwájú.Ní bí a ṣe ń kó ìròyìn yìí jọ. Iye ...
Read More »Ẹ wọ ìbòmú tàbí kí ẹ rugi oyin – Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá
Ẹ wọ ìbòmú tàbí kí ẹ rugi oyin – Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá Ọlọ́pàá èwo n tèpè ni àṣà tó gbayé kan tẹ́lẹ̀ , ṣùgbọ́n ní àsìkò kòró yìí, ó dà bí ẹni pé wọ́n ti sún ilé iṣẹ́ ọ̀hún kan ògiri ...
Read More »Kòrónáfairọ̀ọ̀sì kò dí ìgbáradì ètò ìdìbó ìpínlẹ Edo àti Òǹdó lọ́wọ́–INEC
Ó dà bí ẹni pé ń tí ń ṣe Lébáńdé kò s’ọmọ rẹ o, Lébáńdé ń sunkún ọmú, ìyá rẹ ń sunkún ebi, ló díá fún bí àjọ elétò ìdìbò Nàìjíríà ti kéde pé àjàkálẹ̀ àrùn apinni léèmí coronavirus kò ...
Read More »Aye̩ye̩ o̩jó̩ò̩bí Sikiru Lemon
Aye̩ye̩ o̩jó̩ò̩bí Sikiru LemonBí a bá dájó̩, o̩jó̩, á pé, bí a dósù, osù á kò. Gbogbo o̩jó̩ ko̩kàndínló̩gbò̩n, osù ké̩rin o̩dún ni o̩jó̩ò̩bí Alhaji Sikiru Lemon. Yorùbá bò̩,wó̩n ní “àìbá wo̩n sí níbè̩ ni àìbá wo̩n dá síi”. Ìwé ...
Read More »Èmi àti Olure̩mi yege àjàkálè̩ àrùn covid-19 – Tinubu
Asiwaju agba fun egbe oselu APC, Asiwaju Bola Ahmmed Tinubu ni oun ko ni arun ajakale coronavirus bi gbogbo eniyan se n gbee poori enu. O ni awon kan ni oun ti wa ni igbele olojo merinla pelu Oluremi. Awon ...
Read More »Ní Kàdúná, òfin kónílé ó gbélé yóò tẹ̀síwájú fóṣù kan
Àwọn àgbà bọ̀ wọ́n ní bí iná ò bá tán láṣọ, ó seése kí ẹjẹ wọ̀rù wọ̀rù ṣẹ́kù lórí èékánná. À ti pé, ogun tí yóó bá wọ lé kóni, ọ̀nà la tií pàdé rẹ̀. Ìjọba ìpínlẹ̀ Kàdúná ti kéde ...
Read More »Iwure AJE
Iwure AJE Toni. Aje wa fii ile mii se ibugbe ❗❗❗ Aje iwo lobi Ogun ilu Aje iwo lobi Olufa Aje iwo lobi onipasan owere Oyale asin win bear asin win dolowo Oyale asi were oso asi were di aniyan-pataki Aje ...
Read More »