Home / Iroyin Pajawiri (page 120)

Iroyin Pajawiri

Akoni osere onitiata: Bimbo Thomas gbayi!

Orisiirisii eniyan lo wa laye pelu agbara inu eleyii ti Oba oke da mo onikaluku won. Eyi ti Oluwa fun Bimbo Thomas lo je eyi to jo mi loju ju. Yato si wi pe Edua oke fun lebun ise tiata ...

Read More »

“Ile ise MTN le kogba wole ti won ba sawon itanran tijoba pase re” – Minisita

Minisita tuntun fun eto ibanisoro, Ogbeni Bayo Shittu ti so wi pe ile ise MTN eka ti orileede Naijiria le kogba wo le ti won ba san owo itanran ti ajo ti n risi eto ibanisoro, Nigerian Communications Commission (NCC) ...

Read More »

Awon Obirin to n binu si oludari CRIN niluu Ibadan bora sile nihoho

Awon Obirin to n binu si oludari CRIN niluu Ibadan bora sile nihoho Olayemi Olatilewa Gbegede gbina niluu Ibadan lojo Monde to koja yii nigba ti awon osise ibudo imo ti won ti n sewadii ijinle nipa koko, Cocoa Research ...

Read More »

Atelewo ni mo bala

Ki n to so die fun yin lara itan igbesi aye mi kan ti mi o le gbagbe laelae. Se e ko gbagbe alaye ti mo se fun yin lose to koja? Lara ona ti eniyan le fi se se ...

Read More »

Se atunbotan aye ti de ba Madueke ni?

Foto tuntun Diezani Allison-Madueke ni yii, minisita fun epo robi nigba kan ri, eni ti won fesun jegudujera kan niluu London. Won ni ara madaamu naa ko ya rara. Joojumo si ni ipo ilera re n buru sii. Arabirin naa ...

Read More »

Okiki fi Oore Ofe gbe Femi Solar jade: Fidio orin tuntun yii leku!

Femi omo Oladele ti gbobo eniyan mo si Femi Solar ti fi gbogbo awon ololufe re lokan bale pelu fidio orin re tuntun to pe ni GRACE nigba to n fi die ninu fidio naa to won lenu won. Gege ...

Read More »

O se o Eledua ! Alaafia ti n pada sara Oliseh

Akonimoogba egbe agbaboolu Super Eagles, Sunday Oliseh, si wa ni ile iwosan niluu Belgium nibi to ti n gba itoju lowo. Iroyin tuntun to te Olayemi Oniroyin lowo lati enu awon dokita isegun oyinbo ti n toju re fi ye ...

Read More »

Oko ajagbe jale moto kekere lori ni Pota

Ijamba oko yii lo waye lale oni ni masose ilu Port Harcourt si Aba. Oko ajagbe kan lo yi le mo kekere kan lori eleyii ti eniyan wa ninu re.

Read More »

Gobe Sele Nigba Ti Omo Yari Wi Pe Oun o ni fohin

Yorùbá Dùn shared the following link and had this to say about it: Oloorun ni omo naa, ko fe ki won ba fohin re lero ni won ba mu lele fun un. Nje ohun to buru wa ninu igbese ti ...

Read More »

Awon ologun yibon fun okan lara awon to pe fun Biafra ni Pota lonii

Leyin ti awon omo ologun yinbon pa okan lara awon oluwode ti won pe fun idasile Biafra, ibon tun ba okan lara won lonii niluu PORT HARCOURT.

Read More »