Home / Demo Blog With Mappage 106

Demo Blog With Map

Idajo mi ree…

Leyin gbogbo atotonu awon agbejoro mejeji ati iwadi to peye, ariipe ojebi esun ti a fikan e, nitori na idajo mi ree, ile ejo yi so e sinu: i) igbega; ii) aseyori; iii) idunnu; iv) ayo; v) ire owo; vi) ...

Read More »

Idile Alayo Toni

Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wipe a ku dede asiko yi, mo si ki awa ololufe eto Idile Alayo wipe e ku abo sori eto wa, eto yin, eto Idile Alayo ti ose yi. ...

Read More »

Ogulutu Oro Toni

Hummmmmm mase beru ‪#‎eniyan‬ ju ‪#‎Eledumare lo… ‪woo orewa‬ Kosi nkan tenikan o fi enikan Se,gbiyanjuy latile koju ota re loni,jeki o mo wipe Akinkanju eyan nio ‪#‎nje‬ O mo wipe toba ti nberu eyan ju yio pada sorare di Olodumare niwaju ...

Read More »

Eeto Owe L’esin Oro 4

Mo ki gbogbo wa kaabo si akotun eeto yin, eeto wa owe l’esin oro. Laakoko, mo dupe lowo Olodumare ti o funwa ni oore-ofe lati tun pade loni, leyin igba ti a dagbere fun eeto ni ose to koja. Moki kabiyesi ...

Read More »

Olojo Ibi Toni

Mo layo lati so fun yin wipe oni ni ojo ibi Alagba Oluwakayode Olamilekan Adekoya Ijeni ti won je okan gboogi ninu ebi Omo Yoruba. Okan pataki ni won je lara awon majekobaje ilu yi, oloye nla niwon laafin Olumoye. ...

Read More »

Ibeere Toni: laiye ‪#‎Ijohun ati ‪#‎Aye Ode oni

Ojuwo lefi wo asa ila kiko laiye ‪#‎IJOHUN‬ ati ‪#‎AIYE_ISIN‬ …..nje odara kamo ko omo wa nila bi???

Read More »

Sacrifice (Ebọ; Etutu)

Sacrifice (Ebọ; Etutu) Medium: Chinese Bamboo on bond paper Atelewọ ni o hu’run hèùhèù Dia fun Mofẹ́ẹ́ní Tín bẹ láàrín Òsììrí Tín bẹ láàrín ìpọ́njú To wá nlọ rèé k’owó lọ’dọ̀o Kìífẹání Ẹbọ ni wọ́n ní kó ṣe O gbẹ́bọ, ...

Read More »

Yoruba Du ‘n ka

Yoruba dun-un ka yoruba e komo yin o, ko tun le ko ko tun le so ede abinibi. A~ AJA, B~ BATA, D~ DOJE, E~ EJO, E~EYE, F~ FILA, G~ GELE………. A B D E E F G GB H ...

Read More »

Odu merindilogun re o

Read More »

Foto: Ara Kenge !

E bami kira fun Ife….gbosa, gbosa, gbosa  

Read More »