eku ojumo gbogbo awa omo yoruba rere asikoyi atuwa lara ooooo Ase, ebami dasi oroyii, aare orile ede naijiria yii muhammedu buhari ti yowo yose kuro lori oro epo, epo tiwa di N145 per littre, sugbon eje karantipe nigbati ijoba ana ...
Read More »Demo Blog With Map
Gbolun kan fun baba oni bata yi
Eku dede asiko yi ooooo. E jo eyin omo ilu mi
Read More »Oruko Kan Fun Iya omode yii ?
Eyin Eniyan mi Eje Kia Rerin die. Oruko kan fun iya omode yii ?
Read More »Oro ton’lo Lowo bayi: E wo tomato timo ra ni 500 naira
Eku Dede asiko yio eyin eniyan Atata tin GBE inu ilu Yoruba Atata, oro tonlo Lowo bayi ni mo muwa oro elo obe to won gogo yi ma ni mofe kia soro Lorie o. E wo tomato timo ra ni ...
Read More »Ibeere Toni: 15.05.2016
Nje Iwo leso “FACEBOOK PASSWORD” re fun Ololufere????? Huuum ema paro ooo
Read More »Arewa Asa Toni: Afeez ati Mide Martinez Abiodun
Ko so’ogun mo bee si ni ko so’ote mo ni igbeyawo eleyi ti o ku die ko dojubole. Oserekunrin Afeez Abiodun “Afeez Owo” ati iyawo re Oserebinrin Mide Martin ni ti mu ife won padabo sipo. Laipe yi ni edeaiyede ...
Read More »Iwure Owuro: 14-05-2016
E MAA WI TELE MI : ….. *Fitila ogo mi ko ni ku. *Aso iponju ko ni se dede orun mi. *Oluwa ba mi segun ota ile. *Edumare ba mi segun ota ode. *Ina omo ko ni jo mi. *Ina ...
Read More »Aku ojumo lokun !
Lobinrin wa se dada laji bii.. Adupe lowo OLODUMARE too mu emi ati iwo losii ipo oku lati ano too tun jiwa pada saiye, si aye rere nitori gbogbo eni bati sun ti oku ope ni fun ODUMARE.. Moo wa ...
Read More »Ogulutu Oro Toni: 08.05.2016
Hummm wo oremi banuso mobayan so tori inu jin. # wo Opolopo ore lo nfara han gegebi ota Oplopo ota naa losi nfi ara han gegebi ore….. # nje Otie mo pe opo alangba lo dankun dele ao kuku mo ...
Read More »Iki’Ni Fun Ayeye Ojo Awon Iya Wa
ORIN : “E bami KIRA fun #Mama mi.. #Orisa bi #IYA o.. Ko si Laye… …………….. Iya mi.. Abiyamo lojo Ogun le.. Abiyamo Oloja Aran Abiyamo tii fojooumo wa ko le Dara fun Omo… …………………… Ki Emi gbogbo Awon #IYA ...
Read More »