Opolopo ni i pokiki Olajumoke Orisaguna omo oniburedi gege bi oloriire ti Edumare da lola ojiji pelu bo se se alabapada agbaoje ayaworan ati olorin ti n je TY Bello. Laaarin iseju kan, omo oniburedi di orekelewa oba onise oge. ...
Read More »Demo Blog With Map
Igbeyawo Ooni Ile-Ife fo yangayanga?
*Oba Ogunwusi n mura lati se igbeyawo tuntun Lose to koja ni awon aheso oro kan be sile nigboro eleyii to ti bere si ni mu awuyewuye lowo bayii. Lara awon oro naa ni eyi ti n wi pe, ...
Read More »Fayose setan lati ya awon osise lowo ra moto nipinle Ekit
“Ilaji owo osu won nijoba yoo ma yo fi san gbese naa” -Komisanna isuna owo Gomina Ayodele Fayose ti yanda owo to le ni igba milionu owo naira (N236,860,000) gege bi owo ti won ya soto lati ya awon osise ...
Read More »Gomina ipinle Kwara ti da Jelili oniso lola
*Femi Adebayo n wonu oselu lo diedie Nibayii, gomina ipinle Kwara, Abdulfatah Ahmed, ti yan ogbontarigi onisetiata, Femi Adebayo, gege bi oluranlowo pataki nipa ise ona, asa ati irinajo-afe (Special Assistant on Arts, Culture and Tourism). Osere ti inagije re ...
Read More »Kootu fi leta iku le Rev. King lowo
*Won ni ki won yegi fun un leyin to pa omo ijo re Reverend King Opin irin ajo ti de ba Rev. Chukwuemeka Ezeugo ti inagije re n je Reverend King nigba ti ile ejo to gaju yan-anyan, Supreme Court, ...
Read More »Osika egbon pa omo aburo re tori owo
Ogbeni Samuel Omosaba, eni odun mejilelogoji (42), ni owo awon olopaa ipinle Ondo ti te bayii pelu bo se ge ori omobirin, eni odun meta (3), to je omo aburo re lati fi sogun owo ojiji. Isele yii lo waye ...
Read More »Awon igbimo Olubadan foju Seriki gbole ni kootu
*Won ti dajo iwuye Adetunji gege bi Olubadan tuntun Gege bi oro awon Yoruba to wi pe, ti oba kan ko ba ku, oba mi ki i je. Eleyii ni awon igbimo Olubadan tile Ibadan tele pelu bi won se ...
Read More »Se e ti gbo nipa Beewealth-Textiles?
Arambara aso oge mbe lowo Beewealth-Textiles!
Read More »“Efon ti n fa kokoro Zika wa ni Naijiria, kosi ti gboogun”- Minisita Ilera
Minisita fun eto ilera, Ojogbon Isaac Adewole, ti se idaniloju alaye wi pe, efon abami ti n sokunfa kokoro Zika ti ko gboogun ti wa ni Naijiria. Bakan naa lo si ro awon eniyan lati se ohun gbogbo ni ikapa ...
Read More »Bayii ni Jumoke Orisaguna omo oniburedi se di oloriire
Awon foto re wa nisale
Read More »