Demo Blog With Map
Ambode ti yan oga agba tuntun fun ileewe LASU
Gomina Ipinle Eko, Ogbeni Akinwunmi Ambode ti yan Ojogbon Olanrewaju Fagbohun gege bi oga agba tuntun fun ileewe Ifafiti ti ipinle Eko, LASU. Ikede yii lo waye ninu atejade ti komisanna fun eto iroyin ati agbekale ilana, Ogbeni Steve Ayorinde ...
Read More »Awon tisa ipinle Kwara taku sori idasesile ti n lo lowo
http://www.olayemioniroyin.com/ Idasesile awon oluko alakobere to ti bere lati ojo Aje to koja yii nipinle Kwara ni awon egbe oluko ti temu mo o wi pe yoo si ma tesiwaju ayafi ti ijoba ba san gbese owo osu meta ti ...
Read More »Ohun to pada sele si maanu to lo gbadun ara re nile asewo buru jai
Maanu yii lo lo gbadun ara re nile asewo kan niluu Benin. Aisanwo leyin igbadun lo di ohun ti won da igbati jo fun un.
Read More »Senato ipinle Ekiti pin iresi fun awon eniyan bi Fayos
Awon eniyan ti won gbe ni agbegbe ekun Guusu Ekiti gbajo tilu tifon nigba ti arabirin Biodun Olujimi ti n soju won nile igbimo asofin agba Abuja si obitibiti ounje wolu l’Ojobo ose to koja yii. Apo iresi, ororo ati ...
Read More »“Ayojuran ni Mimiko lo se niluu Bayelsa”- Egbe APC
Awon omo egbe oselu APC eka ti ipinle Ondo ti bu enu-ate lu Gomina Olusegun Mimiko ti awon kan tun pe ni Iroko gege bi asaaju ti ko mo eyi to kan lati muse. Atejade yii lo jade nigba ti ...
Read More »Laasigbo to be laaarin Olubadan ati Gomina Ajimobi
Awon agba ti yanju laasigbo to be sile laaarin Olubadan ati Gomina Ajimobi *Wahala naa sele leyin ti Olubadan fi Ladoja je Osi Olubadan Gomina Abiola Ajimobi Ikunsinu lo bere laaarin Olubadan tile Ibadan, Oba Samuel Odulana Odugade ati gomina ...
Read More »“Awon irinse ti a n lo ti darugbo”- Oga panapana ilu Eko
Oga agba ileese panapana ti ijoba apapo, Federal Fire Service, eka ti ipinle Eko, Ogbeni Aderemi Olusola Theophilus ti sapejuwe ikiyesara gege bi ogun-ajisa lati dena ijamba ina abaadi. Ninu oro re, eleyii to so lori telifisan ipinle Eko, o ...
Read More »What Yorùbá game are these girls playing ??
Aye awon asewo nile awon omo yahoo-yahoo
Bi yahoo-yahoo ni won ni abi ogun oloro ni won gbe, ta lo mo. Sugbon o daju wi pe, eni to n sise gege bi omoluabi ko ni da iru eleyii lasa wo laelae. Ori ayelujara ni aworan yii ti bere ...
Read More »