Demo Blog With Map
E wa wo ohun ti omo Naijiria kan an se lori afara
Mo ri okunrin aro kan ti ko lapa kan lori afara ti awon elese n gba soda niluu Eko. Okunrin naa n fi igbale gba gbogbo ori afara laise wi pe enikeni gbese naa fun. Isesi okunrin naa wu mi ...
Read More »Awon foto ayeye isinku Mama HID Awolowo
Eyi ni die lara awon foto to jade nibi eye ikeyin ti won se fun Mama HID Awolowo eni ti won pada sin lojo karunlelogun osu kokanla odun yii, 25/11/15. E tesiwaju lati wo awon foto to ku.
Read More »Egbe APC Kogi ti yan oludije gomina tuntun
Leyin gbogbo rukerudo oselu to ti n sele nipinle Kogi, eleyii to bere leyin iku Abubakar Audu, awon egbe APC ti yan Yahaya Bello gege bi eni ti yoo ropo Audu to ku. Ogbeni James Faleke naa si ni won ...
Read More »E ba wa dasi oro yii: Ninu ipo ati iya eni, e wo lo gaju?
Leyin ti won fi Sanusi je Emir tilu Kano, oba. Ilu Kano si gba wi pe oosa ajiki bi iya ko si laye. Eleyii lo mu gomina banki agba ile yii nigba kan ri teriba niwaju yeye to bi i ...
Read More »Eto idibo gomina ipinle Kogi di fopomoyo
*Faleke n binu, ara ilu n sofo *Iwe ofin ruju mo awon amofin loju *Won tun ni kan fomo Audu je gomina apapandodo Leyin iku Abubakar Audu, oludije fun ipo gomina labe egbe oselu APC nipinle Kogi, eni to jade ...
Read More »Se Gbenga Adeboye lo ko Wale Dada nise sorosoro?
Lori eto Miliki Express lori telifisan Orisun ni won ti gba Adewale Dada TheGood gege bi alejo pataki ni nnkan bi osu meloo kan seyin. Lori eto naa ni won ti beere lowo enikan to ti fi igba kan dije ...
Read More »Yemi Osinbajo: Ori taa fi sewe
Igbakeji Aare, Yemi Osinbajo nigba to wa nile iwe alakobere Corona School, Lagos. Awon Yoruba bo, won ni ori taa fi sewe kii kuro lorun eni taa ba dagbalagba.
Read More »E wa wo ohun ti oludije ipo gomina n se lagbala pelu aya re.
Eng Seyi Makinde, okan ninu awon oludije ipo gomina nipinle Oyo, labe egbe oselu SDP ninu eto idibo odun 2015 to waye ni yii pelu aya re. Gege bi iwadii Olayemi Oniroyin lati enu awon to sun mo eni ti ...
Read More »Atelewo eni ki i tanni i je
Awon Yoruba bo, won ni amukun-un eru re wo, o ni oke le n wo, e wole. Ojuse awon obi ki i se lati pese ohun ti awon omo won ba n fe nikan, bikose lati sakiyesi iru ebun ti ...
Read More »