Home / Demo Blog With Mappage 137

Demo Blog With Map

Tinuola Oyindamola pegede!

Oni ni ojo-ibi Omidan Tinuola Oyindamola, okan ninu awon ti won karoyin wa lojoojumo.  Adura wa ni wi pe ke e dagba ninu ogbon, ola ati alaafia.

Read More »

Ofin mokanla to le mu awo ara dabi omo tuntun jojolo

Orisun 1 E yee sa ara yin sinu oorun koja bo ti ye lo. Paapa julo, e sora fun awon oorun lati bi ago mewaa aaro si ago meji osan. Orisii oorun yii a maa mu ki awo eniyan o ...

Read More »

Dele Momodu se afihan Madueke nigba keji

Fun awon ti ko mo, Dele Momodu ni oniroyin akoko to koko se afihan foto Diezani Alison-Madueke. Eleyii to ya nigba to se abewo si minisita fun epo robi nigba kan ri ni ilu London.Oga Dele Momodu ti pada se ...

Read More »

“Iyawo mi n yale, o tun bimo ale fun mi”: Alabi yari ni kootu Ikorodu

Orisun   Ogbeni Alabi Rasheed, eni odun mejidinlaadota (48) ti gbe iyawo re, Sherifat, lo si ile ejo lati tu yigi igbeyawo odun mewaa to wa laaarin won ka lOjobo ose to koja yii. Gege bi alaye Alabi ni Ikorodu ...

Read More »

Emir tilu Kano se abewo si awon to farapa ninu ijamba Boko Haram

Emir tilu Kano, Muhammadu Sanusi II, se abewo si awon to farapa ninu ijamba Boko Haram to waye niluu Kano nibi ti aimoye awon eniyan ti ku.

Read More »

Baalu Aare Buhar ti bale niluu Iran

Aare Muhammadu Buhari ti bale ni Tehran to wa ni orileede Iran nibi ti yoo ti maa joko se ipade eleeketa iru e ti egbe awon orileede ti n gbe epo robi jade fun awon orileede agbaye.

Read More »

Saraki gba Basketmouth lalejo niluu Abuja

Aare ile igbimo asofin agba, Bukola Saraki, gba Basketmouth lalejo ninu ile re to wa niluu Abuja

Read More »

Adanwo ni oro ile aye: Iku Abubakar Audu gba arojinle

Titi di akoko yii, enikeni ko le so pato ohun to sekupa oludije ipo gomina labe egbe oselu APC ni ipinle Kogi, Abubakar Audu. Se ise aye ni abi amuwa Olorun oba? Ohun ti ko ye enikan, kedere ni niwaju ...

Read More »

Awon akekoo LASU yari, won ni awon alase n ko leta si yanponyanrin

Lati Ọwọ Olayemi Olatilewa Awon omo egbe akekoo Ifafiti tilu Eko, Lagos State University Students Union (LASUSU) ti bere si ni fariga pelu ifehonuhan latari bi awon alase ileewe naa se fi owo kun owo igbaniwole awon akekoo tuntun. Ifehonuhan ...

Read More »

“Idagbasoke awon akonimoogba gbodo je koko fun NFF” – Amodu

Shuaibu Amodu, okan lara awon igbimo oludari ajo NFF ti so wi pe ona kan pataki lati se igbelaruge fun ere boolu alafesegba abele ni nipa sise eto idagbasoke fun awon akonimoogba ere boolu ile Naijiria. Oro yii ni Amodu, ...

Read More »