Home / Demo Blog With Mappage 161

Demo Blog With Map

Kini Won Npe Iru oko yi ni ede Tire ?

Read More »

E bami Dasi Oro yi Eyin elegbe mi…

  Ninu Obi Eni tabi A’ya Eni, ewo lose pataki ?

Read More »

Aje olokun yo fiso sile gbogbo wa ooo

AJÉ Iwọ́nrín Olókun a bi ara á ‘le koko bí ọta, Òhun l’ó d’ifa fún orí Àpéré ọ̀nà ọmọ a t’Àkàrà ṣ’ọlà.. (Ajé brings prosperity. I wish all Ifa University members a prosperous Ifa year. )Aṣẹ.

Read More »

Awure ki Ori gbe ni:

Awure ki Ori gbe ni: Ori mi gbe mi re Ilu Ilaje Ibi kedere ni Ela gbemi lo Ori gbemi re Ilu Ilaya Ibi kedere ni Ela gbemi lo Sebi Iregbogbo lo n so ju Aje Iregbogbo ni se oju ...

Read More »

Gbogbo oju to nwo aworan yi…

Gbogbo oju to nwo aworan yi eni wole aisan won ni tayin lofa aburu ooo ao ni ri ogun ada njinan ooo !! Ase !

Read More »

Grandson Blows Hot Again! Hotter Actually!!

Lets hear your thoughts in the comment box bellow.

Read More »

Lobatan: Se pasto ni kape Eleyi ni abi satani (Satan) ninu bibeli ?

Oni ki awon omo ijo Bora won si Ihoho ki oun tole gba adura fun ti awaon oponu omo ijo si bora won si Ihoho ni ita Gbangba, Ibere timo fe bere lowo awaon elesin cristeni ni pe se ara ...

Read More »

Nje iwo le fe iyawo ti ori re paa bayi?

Read More »

Tani o Mo Oruko Kokoro Yi ?

Edakun, tani mo Oruko ti won pe Kokoro yi ?

Read More »

Moki gbogbowa wipe aku ewu osu titun ti o wọle de wẹrẹ waba waa !

Mogbaladura wipe ogun aṣeti koni je tiwa ninu osu na,eni na tuni ọjọ (ẹtì) ti wonpeni (friday)…olodumare koni je ki akoju ogun aṣeti nile aye emi ati iwọ… Ẹni tikole tele,ẹniti wa ọmọ latibi,ẹni fe aṣerori lori adawole ẹ,ẹni todawọ ...

Read More »