Home / Demo Blog With Mappage 166

Demo Blog With Map

Egbo eyin eniyan mi Kinni Opin eda laye?

Edakun e ba wa dasi oro to nlo Egbo eyin eniyan mi Kinni Opin eda laye?

Read More »

E ku ojumo eyin omo ile kaaro ojiire. Se daada ni?

Mo gba l’adura wipe bi a tin jade lo fun ise oojo wa, ao ni ko el’esu l’ona. Iko ki n ko ejo l’ese, ayun lo ayun bo l’owo n yun enu. Atepe ni ese n te’na. Ire ila oorun, ...

Read More »

Ogboni – Isese Lagba

Read More »

IWURE ODUN TUNTUN 2015

IWURE ODUN TUNTUN A si ku odun, a ku iyedun. Olodun a wo omo fun wa. Kewekewe koni ko wa l’omo lo. Aseye ni alakan ns’epo ti e Aseye ni tiwa o. Aseti, akoti koni kan wa T’oko, t’aya ati ...

Read More »

Ẹ̀ta Òkò

Read More »

OOOOOREyeyeoooooGBEMI ninuODUNyiOOOOO!

Ase !!

Read More »

IFA NI KASOPE, KASOPE

IFA NI KASOPE, KASOPE MO NI KASOPE KASOPE IFA NI KOMO EKU O SOPE OMO EKU LOHUN LOPE DA IYAN LOMO ARAYE NFI OMO EKU JE IFA NI KASOPE KASOPE MO NI KASOPE KASOPE IFA NI KOMO ERAN O SOPE ...

Read More »

Opon Ifa !

Read More »

Gbolohun kan fun Arakunrin ti Adire’re nsalo nijo Keresimesi

Read More »

ORI……ori yeye nii mo GUN……

Ase Oriwa konibabode…..Ogbo Ato lankira ni’ledi……Ogun Lakaaye adowo fomo Awo

Read More »