Oṣù Òkúdù á yanjú gbogbo ohun tí ó ń dùn wá lọ́kàn Ẹnikẹ́ni ò sì ní bá wa du’re ayọ̀ wa. @AlamojaYoruba
Read More »Demo Blog With Map
Bí ewúrẹ́ bá bojú wo ẹ̀yìn
Á fi èpè fún elépè Mo sé ní ìwúre wípé gbogbo ọ̀tá tí o bá ń robi tàbí sebi sí èmi àti ẹ̀yin lẹ́yìn yoo ma fí orí ara wọn gbe láṣẹ Ọlọ́run Olódùmarè Àsẹ Eu oro para que qualquer inimigo ...
Read More »Ọmọ: Ẹ̀bùn Edùmarè !
Ẹ̀bùn Edùmarè ni ọmọ Ẹ̀rí ìfẹ́ rẹ̀ sí wa ni wọ́n Èdùmàrè à ń bẹ̀ ọ́ Bá wa wo àwọn èwe yè Fi wọ́n fún àwọn tí ń wojú rẹ fún ẹ̀bùn wọn Má ṣe jẹ́ kí wọ́n kú mọ́ ...
Read More »Pari Owe Yii
Ohun to wa leyin Ofa!
Read More »Asiri àwo kintú,
Asiri ẹ̀tú kintú, Iwọ iwori bógbè IFA, Ki owá bo asiri mi, Iwọ iwori bógbè. Mogbá ládùrá wipè loni ọjọ àbámẹtá asiri gbógbó wa koni tu kotobó lailai,gbogbo abá ti aba da loni yio jẹ mimusẹ, Aṣẹ̀ aṣẹ̀ aṣẹ̀. Aṣẹ̀ aṣẹ̀ aṣẹ̀.
Read More »Àwon tí ó n gbélè sunkún síta fún ìrànlówó nígbà tí àwon adigunjalè jàwón lólè ní Bayelsa.
Àwon olùgbé Opolo ní Yenagoa ìpínlè Bayelsa ni ìbèrùbojo ti gba okàn won léyìn tí àwon adigunjalè jà won lólè tán. Gégé bí ìròyìn se so, àwon olè yí kojá ogbòn tí won sì gbé àwon ohun ìjà olóró lówó ...
Read More »Mi ò le fé okùnrin tí kò bá le bámi sùn fún wákàtí méjìlá sí méèdógún.
Mi ò le fé okùnrin tí kò bá le bámi sùn fún wákàtí méjìlá sí méèdógún. Arábìnrin kan tí a kò fi taratara mo orúko rè súgbón tí kò le jú omo odún méèdógún sí ogbòn kan ni ó so ...
Read More »Gómìnà ìpínlè Osun tí a sí Oyetola gba àwon èèyàn là nínú ìjàmbá okò tí ó selè ní òpópónà Ibadan sí Èkó.
Ókéré jù èèyàn tí ó kojá néjìlá ni ó fara pa nínú ìjàmbá tí ô selè ní òpópónà Ibadan lo sí Èkó sùgbón tí Gómìnà Oyetola ti gba wón kalè. Ògbéni Isiaka Oyetola náà n lo sí èkó ni ojó ...
Read More »Bánà Omo Egbé APC tí ó n lo fún Gómìnà ìpínlè Kwara ni won lè sí iwájú agboolé àwon Saraki.
Bánà Omo Egbé APC tí ó n lo fún Gómìnà ìpínlè Kwara ni won lè sí iwájú agboolé àwon Saraki. Ìròyìn kàyéfì… Omo egbé APC tí a mò sí Abdulrasaq Abdulrahman, tí ó n díjé fún ipò Gómìnà ìpínlè Kwara ...
Read More »Tope Osoba se ayeye ojó ìbí rè nígbà tí ó pé omo odún métàlélógbò (33) pèlú àwon àwòyanu àwòrán.
Temitope Osoba tí gbogbo ènìyàn mò sí Tope Osoba jé òsèré orílè èdè Nìjíríà tí ó sì tún jé olùko eré, won bí i ní ojó kejì osù kejìlá, odún 1985. Ó jé jé akékòó jáde ilé-èkó gíga ifáfitì Olabisi ...
Read More »