Ò n lò èro ayélujára (Facebook) Bucandy Ayo Abubakar, tí ó jé onísé abe pín àwòrán ara rè àti bàbá rè àti bàbá rè onísé abe ti se isé-abe fún aláìsàn kan tí ó ní àìsàn “Appendix” ó sì ko ...
Read More »Demo Blog With Map
Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbeyàwó tí àwon àgùnbánirò méjì yí yà ní ìpínlè Imo, láti e n lé (Hello) di e pèlé(Hi) títí di ìgbéyàwó.
Ìgbéyàwó eka-èkó (departmental weeding) ni, ìgbéyàwó àgùnbánirò ni tí ó bèrè láti e n lé di e pèlé, tí won wá di orè tímótímó eka-èkó tí won sì padà di olólùlé eka-èkó báyìí ó ti di ìgbéyàwó eka-èkó. Ihekuna Ann ...
Read More »Juliet Ibrahim ti fé Iceberg Slim won sì ti se ìgbéyàwó ní kóòtù .
Juliet Ibrahim ti fé Iceberg Slim won sì ti se ìgbéyàwó ní kóòtù . Afòròdárà (rapper) tí ó n jé Iceberg Slim àti òsèré bìnrin Juliet Ibrahim ti so ìfé won pò pèlú ìfenukonu léyìn tí won ti se ìgbéyàwó ...
Read More »olópàá kan ní Enugu ti mú àwon òdóbìnrin méjì nígbà tí won n rìn l’ójú ònà látàrí aso ìwòkuwò tí won wò.
Gégé bí eni tí ojú rè to se so, tí ó sì gbe sí orí èro ayélujára se so, olópàá kan ní ìpínlè Enugu ni a ti fi èsùn kàn wípé ó mú àwon òdóbìnrin méjì tí won wò aso ...
Read More »” Mi ò l’óyún” Tiwa Savage so béè láti dékun ìròyìn tí kò múná dóko tí won n so nípa rè.
” Mi ò l’óyún” Tiwa Savage so béè láti dékun ìròyìn tí kò múná dóko tí won n so nípa rè. Ìròyìn tí ó gbòde kan láìpé ni wípé Tiwa Savage ti l’óyún tí Linda Ikeji so súgbón Tiwa Savage ...
Read More »Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó tí Nosakhare Ogbemudia àti Ekan Egonmwa yà.
Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó omobìnrin olóògbé Dr Samuel Ogbemudia, Nosakhare. Nosakhare, arewà omo Gómìnà àwon ológun ti ìwò oòrùn télè, olóògbé Dr Samuel Ogbemudi, ti setán láti se ìgbéyàwó pèlú Ekan Egonmwa. Ó sì ti se ayeye ...
Read More »Ota ìbon tí àwon olópàá àti àwon ìgárá olóshà n yìn mó ara won sè sì bá awa kèké kan ní ìpínlè River.
Oní kèké kan ní PortHarcourt ni ó ti kú látàrí ota ìbon tí ó se sì ta ba nígbà tí àwon ìgárá olóshà àti olópàá n yin ìbon mó ara won. Òdókùnrin tí ó jé oní kèké yí ...
Read More »Òdókùnrin yí ni ó ko “666” sí iwájú orí rè.
Bóyá láti jé kí àwon òré rè lórí èro ayélujára(Facebook) tèka wípé àwon féràn rè ni tàbí kí ó fi di gbajúgbajà. Òdókùnrin tí kò dàgbà jù, tí ó sì jé ò n lò èro ayélujára(Facebook), tí a mò ...
Read More »Àwon egbé òkùnkùn Badoo ti pa Ebí tí ó jé méta ní Epe ní ìpínlè Eko .
Àwon omo egbé òkùnkùn tí pa ebí tí ó jé méta tí won sì fi omo kékeré tí ó fi ara pa sílè ní Epe ní ìpínlè Eko. Won ti pa gbogbo ìdílé kan run sùgbón won fi omo kékeré ...
Read More »Ejò nlá kan (paramólè) tí won pa ní agbègbè mi láìpé ní àró yí.
Ní àárò yí nígbà tí mo ti setán láti ma lo sí ibi isé ni mo pàdé àwon ògbéni yí, tí won n yo látàrí wípé won pa ejò, tí mo rò wípé paramólè ni, tí won sì ti gbèrò ...
Read More »