Home / Demo Blog With Mappage 64

Demo Blog With Map

Peter Okoye àti Lola Omotayo se ayeye odú kerin ìgbéyàwó won.

   Olórin , Peter Okoye ti Psquare àti ìyàwó rè , Lola Okoye tí won ti wà papò fún bí odún métàlá se ayeye odún kerin ìgbéyàwó won.

Read More »

A ya àwòrán Bola Tinubu àti Osinbajo.

   Igbékejì Ààre Osinbajo àti baba ìsàlè egbé APC Bola Tinubu ya àwòrán papò lánàá níbi fífi ìwé l’ólè tí okàn lára àwon agbenuso ilé ìgbìmò so lórí bí Ààre Buhari se n gbógun ti ìwà jegúdújerá.

Read More »

Toke Makinwa ti ko àkosílè èróngbà rè fún odún 2018.

    Toke Makinwa ti ko èróngba rè fún odún 2018,tí ó sì ti setán láti gba odún náà towótosè . Lára àwon èróngbà rè ni Olórun, Ebí abbl.

Read More »

Patience Jonathan níbi ayeye ìgbéyàwó omobìnrin asojú ilé ìgbìmò asòfin, Sekibo.

     Aya Ààre télè, Dame Patience Jonathan yo ní àrà òtò láti yé adojú ilé ìgbìmò asòfin Thompson Sekibo bí ó se no àkóbí rè lówó níbi ìgbéyàwó yí ní ìlú Ogun.

Read More »

A ya àwòrán Bola Tinubu àti Osinbajo.

   Igbékejì Ààre Osinbajo àti baba ìsàlè egbé APC Bola Tinubu ya àwòrán papò lánàá níbi fífi ìwé l’ólè tí okàn lára àwon agbenuso ilé ìgbìmò so lórí bí Ààre Buhari se n gbógun ti ìwà jegúdújerá.

Read More »

Òdóbìnrin àtúnbí yí ti sí tàtúù apá rè pèlú irin gbígbóná.

    Òdóbìnrin àtúnbí tí ó jé omo orílè èdè Nàíjíríà, ti jó owó rè pèlú irin gbígbóná ní èróngbà láti pa tàtúù owó rè, gégé bí ó se so wípé èsè ni , ó sì le dínà láti wo ...

Read More »

Àwòrán tí ó yanilénu tí Empress.

Njamah òsèré Nàíjíríà, Empress Njamah tí ó kò láti ní adé orí , látàrí wípé ó ní owó lówó gbe lo sí orí èro ayélujára láti pín àwòrán tí ó rewà ti ara rè. Òsèré yí dàbí eni tí inú ...

Read More »

Fayose se ayeye odún ketàdínlógóta (57)ojó ìbí rè pèlú ìsìn ìdúpé ní sóòsì pèlú ìyàwó rè.

   Gómìnà ìpínlè Ekiti Fayose se ìsìn ìdúpé ní gbàgede Lady Jibowu ti ilé ìjoba fún ti ayeye odún ketàdínlógóta ojó ìbí rè. Àwòrán ibi tí ó ti n dì mó ìyàwó rè.

Read More »

Òbísúárì okùnrin kan, ìyàwó rè pèlú omokùnrin won tí a gbó wípé won sin won ní ojó kan náà .

   Oun tí ó ba ni nínújé gbáà ni ìsìnkú okùnrin kan pèlú ìyàwó rè àti omokùnrin won tí ó kú ní ojó kan náà. A gbó wípé ojó kan náà ni won ma sin wón ní ìpínlè Imo. Èyí ...

Read More »

Ère Nana Akufo- Addo ni Rochas Okorocha fé sín ní Imo.

   Gómìnà ìpínlè Imo, Rochas Okorocha ti se tán láti sín ère ààre Nana Addo ti Ghana ní Owerri nígbà tí ó ti sí ère ti ààre Ellen Sirleaf ti Laberia àti Zuma ti South Africa . Ère náà ti ...

Read More »