Home / Demo Blog With Mappage 89

Demo Blog With Map

Odo Iwoyi – E Gbo Bi Atejise Na Ti Lo

Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wi pe a ku dede asiko yi, mo si ki awa ololufe eto Odo Iwoyi wi pe e ku abo sori eto wa, eto yin, eto Odo Iwoyi ti ...

Read More »

Ko ko’le ko sun ori igi…

Ko ko’le ko sun ori igi Ko ro’ko ko je eepe ile(Ogunda wori) Translation Not building or buying a house does not mean you have to sleep on the top of a tree Not farming does not mean you have ...

Read More »

Òbàrà Méjì No 7.

Whoever this Odu is revealed to, probably during ìtènifá, Ìséfá or Ìdáfá, he/she needs to offer Ebo so as to always receive the blessings of his/her spiritual group in heaven. Ifá make it vivid that this person belongs to a ...

Read More »

I’m Not Scared Of Heaven Because It’s My 2nd Home #Spirituality

I am not religious but I am definitely a spiritual person. I have always said that a religion is for people who are scared of ending up in hell. Spirituality is for those who have already been there…#Proudly Olorisa# #Orisa ...

Read More »

A té o náá…

A té o náá. Hee, a té o náá. Kí o tún ara e té o. Awo kì nlé ikún. Awo kì nlé ejò o. A té o náá kí o tún ara e té. Awo kì nsúré gun igi ...

Read More »

Ejo kini oruko ewe yi

Read More »

Orunmila ni awure emi naa moni awure

  Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a si tun ku isimi opin ose adura wa yio gba o, ori buruku koni je tiwa o ase. Laaro yi mo nfe ki a mo iwulo ewe yi ...

Read More »

Oriki Ori

Ori Onise Apere Atete gbeni ju Orisa Ori atete niran Ori lokun Ori nide Ko si Orisa ti dani gbe leyin Ori eni Ori ni seni ta a fi dade owo Ori ni seni ta a fi tepa ileke woja ...

Read More »

Ikoja aaye pelu aimo iwon ara eni…

Mejeeji ko papo amoo won maa n wo tele ara wo leyin ni. Yorubo won ni, ikoja aaye nii mu ki fulani o kiri odo iyan. Aimo iwon ara eni naa nii sii muki abuke o ko ise atun’ko se.  Emo ...

Read More »

Iwulo Ewe To Wa Ninu Aworan Yi Ninu Odu Ifa OGBEYONU,

Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a sin Ku isimi oni emi wa yio se pupo re laye o ase. Loni mofe ki a mo iwulo ewe to wa ninu aworan yi ninu odu ifa OGBEYONU, ...

Read More »