Ará ilé télè ti BBnaija tí a mò sí Cee-c ti ya àwòrán pèlú Yaw ti Wazobia FM àti Toolz ti Beat FM lénìí nígbà tí won se àbèwò sí won.
Read More »Omobìnrin tí won ti ń wá láti ojó mélòó séyìn, èyí tí ó fi ilé-èkó sílè láti tèlé Òdókùnrin kan ní ìpínlè Delta.
Àwon ebí akékòó bìnrin kékeré tí ó sonù láti bí ojó mélòó séyìn ni a ti gbó wípé arákùnrin kan ni ó wá gbe ní ilé-èkó léyìn isé òòjó náà . Omobìnrin tí ó jé akékòó ní ilé-èkó Okpe grammar ...
Read More »Ilé-ìwòsàn àwon ará Sokoto .
Ilé-ìwòsàn àwon ará Sokoto . Ìyá yí pọ̀ Ó ju omi òkun lọ Èdùmàrè Ìwọ tó o dá Ráábí aláṣọ Dákun má gbàgbé Ráábí eléwé Èdùmàrè ṣàánú mi Iná tó ń jó tálákà ní Nàìjíríà Ó dájú pé ó ju ...
Read More »Omo ìbàdàn
Omo ìbàdàn Ìbàdàn mèsi ògò, n’ílé olúyòlé. Ìlú ògúnmólá, olódò kèri l’ójú ogun. Ìlú ìbíkúnlé alágbàlá jáyà-jáyà. Ìlú Àjàyí , ò gbórí Efòn se fílafìla. Ìlú Látóòsà, Ààre-ònà kakanfò. Ìbàdàn Omo ajòro sùn. Omo a je ìgbín yó, fi ìkarahun ...
Read More »Omo Ibadan ati Ankara Gucci !
Oríkì ìbejì
Oriki Ibeji: Wíníwíní lójú orogún Ejìwọ̀rọ̀ lojú ìyá ẹ̀, Ẹ̀jìrẹ́ ará ìṣokún, Ẹdúnjobí, ọmọ a gbórí igi rétẹréte, Ọkàn ń bá bí méjì ló wọlé tọ míwá, Ọ́bẹ́kíṣì bẹ́kéṣé, Ó bé sílé alákìísa, Ó salákìísà donígba aṣọ. Gbajúmọ̀ ọmọ tíí ...
Read More »Owe Toni: Lati Owo Jude Chukwuka
Ìfé Mi (My Love)
Ìfé Mi (My Love) Eni bíi okàn mi Adúmáradán orenté Olólùfé mi àtàtà Ìfé re ní n pa mí bí otí òyìnbó Lá ì gbó ohùn re Mi ò lè sùn mi ò lè wo Léyìn re kò sí e ...
Read More »ORÍLÈ ÈDÈ MI
ORÍLÈ ÈDÈ MI Nàìjíríà ìlú mi pàtàkì Ìlú t’ókún fún ogbón Pèlú òpòlopò àwon òjògbón Ilé ogbón Tí a ti n hun àgbòn ìwà ìbàjé S’ogúndogójì di ààyò àwon òdó Òsèlú di ohun wón k’èyìn sí Egbé òsèlú di ìkan ...
Read More »Awakò kan tí kò fi ara balè ní ojú pópó ti fi okò fó orí omokùnrin kan ni ìpínlè Edo.
Òdókùnrin kan ni ó se àgbákò ikú òjijì ní ojó mélòó séyìn ní ìlú Jatu ní ìpínlè Edo, nígbà tí ó n gbìyànjú láti fònà sí òdì kejì, arákùnrin yí ni okò tí o n sáré fó ní orí tí ...
Read More »