Home / Tag Archives: Àṣà Yorùbá (page 55)

Tag Archives: Àṣà Yorùbá

Isu Oro bale ro pee…

A da fun eji, ti o ma bowo fun iko Odidere, won ni ko kara nile, Ebo ni ko mu se. Ojo o ni ro ko pa ina iko Odidere, Iko Odidere d’Orisa. Ni Agbara Olodumare ati oruko Orunmila, Gbogbo ...

Read More »

Otura Oriko, wa lo ree silekun ire temi fun mi! Aase!

Hoje também é dia de propiciarmos Olokun. Que a força e o Ase de Olokun abra as portas do progresso e da prosperidade a nossa família criando condições para que todos os obstáculos sejam retirados de nosso caminho. Ikan lowo ...

Read More »

Ewe Yi Je Òkan Lara Awon Ewe Ifa To Dara Pupo

Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a sin ku isimi opin ose, emin wa yio se pupo re laye ase. Laaro yi mofe ki a mo iwulo ewe to wa ninu aworan yi lati inu odu ...

Read More »

Atitare/Itare: Pataki ewe towa ninu aworan yi ninu odu ifa OTURA ORILANA

Aku ise ana o oni a sanwa o, aanu olorun Olodumare koni fiwa sile loni o ase. Laaro yi mofe ki e mo Pataki ewe towa ninu aworan yi ninu odu ifa OTURA ORILANA, ati iwulo e ti o se ...

Read More »

Kini oruko ewe yi ?

Ejo kini oruko ewe yi

Read More »

Oruko wo ni ama pe awon to’n diru’n nilé Yoo’oba ?

E ba mi dahun ibeere yii

Read More »

Bi Ere BI Awada Oorun Odun 2016 n lo Ibi Ati Wo….

Ni iru akoko yi opo ile ise nla nla ni won ngbaradi ati se akosile asekagba ise iriju won fun odun ti nlo sopin yin… Beeni opo osise ile ise wonyi ti a ti fun ni gbedeke nibi ise won ...

Read More »

Odo Iwoyi – E Gbo Bi Atejise Na Ti Lo

Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wi pe a ku dede asiko yi, mo si ki awa ololufe eto Odo Iwoyi wi pe e ku abo sori eto wa, eto yin, eto Odo Iwoyi ti ...

Read More »

A té o náá…

A té o náá. Hee, a té o náá. Kí o tún ara e té o. Awo kì nlé ikún. Awo kì nlé ejò o. A té o náá kí o tún ara e té. Awo kì nsúré gun igi ...

Read More »

Ejo kini oruko ewe yi

Read More »