Home / Tag Archives: Àṣà Yorùbá (page 79)

Tag Archives: Àṣà Yorùbá

Odun 2016 yoo dun bi oyin: E ku odun tuntun

E ku odun tuntun. Odun ayo ati igbega ni yoo je fun gbogbo wa.  Ase. Odun 2016 yoo dun bi oyin. Bee ni. E je ki eleyii je ero yin. Kosi tun maa jeyo ninu awon oro enu yin nigba ...

Read More »

Igbeyawo omo Adewale Ayuba fakiki

Idunnu obi ni ki omo o yan ko si yanju. Omo taa to, to si duro gbeko ni i pada di omo gidi lowo awon obi re. Eyi  ni a le pe ni itan Tiwalade Ayuba lowo baba re. Ayo ...

Read More »

Omiyale-agbara ya soobu ti se ijamba niluu Oba Biritiko

Aimoye dukia lo ti sofo bayii latari iji nla pelu agbara ojo ti n wo odindi moto sare ni ilu England bayii. Isele buruku yii lo waye latari ojo alagbara kan to si lule to si bere si ni se ...

Read More »

Oserebirin wo leyii, Se e damo bi??

Read More »

E wo ohun ti enikan so nipa ile epo Bovas to wa niluu Ibadan

Awon arije ni madaru, ika, odaju, ole, wobia, wonbiliki le po ni Naijiria loooto, sugbon awon eniyan rere ko ti tan lawujo wa. Okan ninu won ni alase ile epo Bovas to kale silu Ibadan. Bakan naa ni awon eniyan ...

Read More »

Ijamba oko niluu Eko lojo odun keresimesi

Ti e ba muti, e ma wako; ti e ba wako, e ma muti. Okunrin kan lo koja lo sorun lojo odun keresimesi to koja yii ni akoko ti gbogbo eniyan n yo ayo iwasaye Jesu olugbala araye. Ijamba oko ...

Read More »

Owo ti te Jaguda, Mohammed Isah to lu komisanna olopaa meji ni jibiti

Sebi ojo gbogbo ni tole, ojo kan pere ni tolohun. Owo awon olopaa ilu Eko ti te omo gambari onijibiti kan ti oruko re n je Mohammed Isah, to lu komisanna ipinle Ondo ati Anambra ni jibiti. Omokunrin onijibiti naa ...

Read More »

“Kosi ona ti a fe gbegba, ijoba ni lati yo owo iranwo ori epo kuro” – Oyegun

Alaga egbe oselu APC, oloye John Odigie-Oyegun ti fi da awon omo Naijiria loju wi pe, kosi ipadaseyin ninu yiyo owo iranwo ori epo robi. Oyegun lo n soro yii nigba ti n gbalejo awon iko kan lati inu egbe ...

Read More »

“Ajo NFF kii ta agbaboolu soke okun” Aare NFF

Ogbeni Amaju Pinnick to je aare ajo ti n risi ere boolu alafesegba, Nigeria Football Federation, ti fesi lati tako awon aheso kan ti n lo nigboro wi pe, ajo NFF n se bisineesi tita agbaboolu soke okun. O ni ...

Read More »

Esun idigunjale la o fi kan eni to ba gbegidina ti n gbowo odun” Olopaa Ipinle Ogun

Komisanna awon olopaa ipinle Ogun, Ogbeni Abdulmajid Ali ti kede wi pe,ile ise olopaa ipinle Ogun ti wa ni imurasile lati gbogun ti iwa idaran to seese ko suyo lasiko poposinsin odun taa wa yii. Ninu oro Ogbeni Abdulmajid, eleyii ...

Read More »