Ǹjẹ́ ó yẹ kí ó rí bẹ́ẹ̀? asatiwa Leave a comment Ṣé ó tọ́ kí Ojúlówó ọmọ Yorùbá ó torí pé òun di ipò Òṣèlú mú ó máa nawọ́ láti gbọwọ́ pẹ̀lú Ọba Aládé ní gbàgede? Read More » tweet