Home / Tag Archives: oriki

Tag Archives: oriki

Oríkì Fún Ọba

Kábíyèsí Ọba Olúwayé, Ọ̀dúndún aṣọ̀’de d’ẹ̀rọ̀, Ọba adé-kí-ilé-r’ójú Ọba ade-kí-ọ̀nà-rọrùn, Arówólò bí òyìnbó, Ó fi’lé wu ni, O f’ọ̀nà wu ni. Ògbìgbà tí n gba ará àdúgbò Ọba at’áyé-rọ bí agogo.

Read More »

Oriki Ori…

Ori Onise Apere Atete gbeni ju Orisa Ori atete niran Ori lokun Ori nide Ko si Orisa ti dani gbe leyin Ori eni Ori ni seni ta a fi dade owo Ori ni seni ta a fi tepa ileke woja ...

Read More »

ORIKI ORILE IREMOGUN

Oju ni mo ro.Ara ilagbede.Omo aworin-tunrin-ro.Ba a ki won nire.Won ki i je.Omo owu ni won fi n je ni.Ojo obe ire ba di meji.Lo dowon-gogo.a ki i bimo nire.Ko pose owo.Eru onire ni i robe ide.Awon iwofa ibe a ...

Read More »