Enikan lo lo ki ore re,ko si ba ore re nile, sugbon o ba okan ninu awon omo ore re nile.
Oni baba re n ko?
Omo naa ni:”Baba mi lo so okun (rope) aye ti o fe ja”
Iya re naa n ko?
Omo naa ni:”Iya mi wa ni ese kan aye ese kan orun”
O da naa egbon re n ko?
Omo naa tun so bayi pe:”Egbon mi n ba iku wo ijakadi owo (money)”.
Eyin ojogbon eniyan, kini itumo awon oro won yii:

i- O lo so okun (rope) aye ti o fe ja.

ii- Ese kan aye ese kan orun.

iii- O ba iku wo ijakadi owo (money).

About The Author

@omooduarere

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Orun Ire Ooooo

ERIN WOOOOOOO. Iku da Oro iku shei’ika, Iku mu eni rere lo.