Home / Àṣà Oòduà / Oju-Abe: Aare Mohammodu Buhari pase fun oga Agba Olopaa

Oju-Abe: Aare Mohammodu Buhari pase fun oga Agba Olopaa

Aare ile wa Nigeria, #Aare_Mohammodu_Buhari ti pase fun oga Agba yan-an-yan fun awon Olopaa nile wa lati tenu bo iwadii lori awon Ajo tiwon da sile lati maa pese Ounje ati Ohun-eelo fun awon Eeyan ti Iko-Onilakaadi-Ajajangbila #BOKOHARAM tiso di Alaini, Sugbon ti awon Ajo naa dari Ounje naa gba ibomiiran lo ki won si fi kele-ofin gbe eni ti iwa-Ibaje-yii ba si le lori ..
.
* OJU-ABE
Taa ni ka bu ?
Se Ijoba ni ko se Amojuto awon Eeyan yii daadaa ni tabi Awon Adaniloro tiwon dari Ounje gba Ibomiiran lo ?
.
Abi ka tile so wipe awon ti Ebi n pa ni Ijoba gbe Ounje ran, Ona da kiwon ma ji Ounje je ?
Abi Awon eeyan yii niwon daju ?
.
Oro ree …..
E bawa so #Oju_Abe nikoo !!!

@ #ORANMIYAN_MAGAZINE

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo