Home / Àṣà Oòduà / Akékòó bìnrin méjì ja ìjàgbara látàrí òrékùnrin ní ilé-èkó gíga ifáfitì tí a mò sí Tai solarin University of Education, ní ìpínlè Ogun.

Akékòó bìnrin méjì ja ìjàgbara látàrí òrékùnrin ní ilé-èkó gíga ifáfitì tí a mò sí Tai solarin University of Education, ní ìpínlè Ogun.

Fídíò àti àwòrán àwon òdóbìnrin méjì tí ó ñ jà látàrí òrékúnrin kan ni ó ti gbalè kan .
Akékòó ni àwon arábìnrin méjì yí àti wípé akékòó ilé-èkó ifáfitì ti Tai Solarin University Of Education ni won, ìpínlè Ogun, won fi èsùn kàn wípé ìjà won dá lórí arákùnrin tí ó ñ se yáhoo yahoo tí àwon méjèjì jo ñ fé.

Gégé bí ìtàn se so, ní ilé ìgbé àwon Akékòó tí a mò sí Hostel ni èyí ti selè, ní ibi tí kò jìnà sí mósálásì Ijele.

About Awo

x

Check Also

Orun Ire Ooooo

ERIN WOOOOOOO. Iku da Oro iku shei’ika, Iku mu eni rere lo.